OSE KARUN-UN
IPAROJE ATI ISUNKI
AKOONU
Iparoje: Ni fifo awon iro tabi siso awon iro nu nigba ti a ba n yara soro. Ti a ba n yara soro, a maa n pa awon iro kan je, awon iro ti a maa n paje ni:

  • Iro konsonanti.
  • Faweli ati ohun.
  • Apapo konsonanti, fawli ati ohun ninu oro.

 Nibi ti a ba ti pa iro je, alafo yoo wa nibe, a o wa pa iro mejeeji po di eyokan. Pipapo apa oro eyo kan ni a mo si isunki.
Se ise = S( ) ise = sise (faweli ‘e’ ni a paje)

 Adiye = adi ( ) e    adie (kons ‘y’ ni a paje)

 IPAJE KONSONANTI
Opolopo iro Konsonanti ede Yoruba ni a le paje ninu afo/oro siso. Eyi ni awon eyo oro ti a ti pa konsonanti je ni ikookan ati ayorisi ipaje

 

OroIro ti a pajeAbajade ipaje (isunki)
Ebibi
Daradara
Olorun
Kehinde
Gbolohun
Olele
Ajayi
Adiye
Jowo
(eibi) b
r
r
‘h’
‘h’
i
y
y
w
Eebi
Daadaa
Oloun
Keinde
Gboloun
Oole
Ajai
Adie
Joo

 
 

Omoluwabi
Adura
Ekuro
Akara
Dara
Akitan
W
r
r
r
r
k
Omoluabi
Adua
Ekuo
Akaa
Daa
Aatan

 Itupale oro ti iparoje ati aranmo ti waye
Eyi ni awon oro ti iparoje ati aranmo ti waye laaarin faweli.

 Eyo oro    konsonanti ti a paje        Aranmo laarin faweli        Isunki
Bawo        bao (w)            “a” ati “o”                boo
Egbewa    egbaa (w)            “e” ati “a”                 egbaa
siwaju     siaju (w)             “i” ati “a”                saaju
otito        Oito (t)            “o” ati “i”                ooto
akike        aike (k)            “a” ati “i”                aake
orirun        oirun                “o” ati “i”                oorun
alila        aila                “a” ati “i”                aala
oyiya        oiya                “o” ati “i”                ooya
edidu        eidu                “e” ati “i”                eedu
otutu        outu                “o” ati “u”                ootu
okankan    oankan            “o” ati an                ookan
efinfin        eifin                “e” ati in                eefin
egungun    eungun            “e” ati un                eegun

 IGBELEWON
1.Kin ni iparoje?
b.Daruko ibi ti iparoje ti maa n waye.

 IWE ITOKASI
S.Y Adewoyin (2006) Imo, Ede, Asa Ati Litireso Yoruba Corpromutt Publishers Oju iwe

 ORAN DIDA ATI IJIYA TI O TO
    Oran dida ati ijiya ti o to

  • Itumo
  • Ohun ti o faa
  • Orisii oran ti eeyan le da
  • Ipa ti oba ati ogboni n ko ninu fifi iya je odaran
  • Orisirisi oran ti eeyan le da
  • Ipa ti oba ati ogboni n ko ninu fifi iya je arufin

 AKOONU
Se Yoruba bo won ni ‘ilu ti ko si ofin ese ko si, bakan naa awon Yoruba ni igbagbo ninu idajo ododo won ki i si i fi ejo se egbe. Bakan naa, won ni elese kan ki yoo lo laijiya nitori idi eyi gbogbo oran lo ni ijiya. Oba, ijoye ati awon ologboni lo maa n se eto idajo ni aye atijo.

 Oran Dida: Ni ti tapa si ofin tabi rire ofin ilu kan koja ni pa sise ohun ti won ni won ko gbodo se tabi sise omonikeji ni ibi. Ohun ti o n fa oran dida orisiirisii ni ohun ti o le fa oran dida, die ninu won niyi:-

 

  • Ojukokoro
  • Iwa imotara eni nikan
  • Aini itelorun
  • Etanu
  • Aigboran abbl.

Orisiirisii oran ti eeyan le da ati ijiya ti o to sii. Eyi ni orisiirisii oran ti eeyan le da:
ipaniyan, ole jija, idigunjale, ifadiya, jibiti lilu, aje sise, biba iyawo oniyawo lopo, lilo oogun ika, gbomogbomo abbl.    Ipa ti oba ati ogboni n ko ninu fifi iya je odaran.
Ipa kekere ko ni oba ati awon ogboni n ko ninu fifi iya je odaran. Gege bi a se mo pe oba ni olori ati alase ilu, ti o n ri si idagbasoke ati aabo ilu, ti odaran ba daran, ti o si ju eyi ti Baale tabi Baale le pari lo, aafin oba ni won yoo mu iru odaran bee lo, ti oba ati awon ijoye yoo si jiroro lori iru iya ti won yoo fi je iru odaran bee. Bakan naa ni awon ogboni naa ko gbeyin ninu fifi iya je arufin.

 IJIYA FUN ILE DIDA
Yoruba gbagbo pe eni ti o ba dale a ba ile lo ati pe eni ba n yo ile da pelu, ohun werewere yoo maa yoo se. Bi eni kan tabi ilu kan ba gbangba, ti o si dale gbangba, orisiirisii ona ni iya le maa gba je odale yii. O le sadeede ku lojiji. Sobia le gbe e sanle ki o ma le dide fun odun meta. o le lu agbana, ijamba si le se e bi ki aake sa a lese, o si le maa se aare ogeu ti ko loju, ti ko si gbo wiwo. Iku ni opin gbogbo nnkan wonyi fun odale.

 Igbelewon

  1. Daruko oran marun-un ti eeyan le da.

APAPO IGBELEWON

  1. Daruko oran marun-un ti eeyan le da.
  2. Kin ni iparoje?
  3. b.Daruko ibi ti iparoje ti maa n waye.

ZT%NY@W) IX!

  1. Ko apeere oro oruko afoyemo mefa sile.
  2. Ko apeere oro oruko aridimu mefa sile.
  3. Ko apeere oro oruko ibi kan mefa sile.
  4. Ko apeere oro oruko aseeka mefa sile

IWE ITOKASI
ASA ATI AWON ORISA ILE YORUBA Oju Iwe 237

ISE ASETILEWA

  1. ________ lo ma koko sele ki isunki to waye A. aranmo B. iparoje C. ihun oro.
  2. Apeere Isunki to waye ninu oro to ni ju konsonanti kan lo ni _______ A. Joo B. Ibebe C. Ponmi.
  3. Se isunki/ipaje awon oro wonyi: edidu, esisu, orisa. A. Eedu, eeesu, osa. B. Eedu, eesu, oosa. C. edu, esuu, oosa.
  4. Ewo ninu awon wonyi ni aranmo maa n waye leyin isunki ati ipaje ba ti waye A. Eeke B. Laelae C. aatan.
  5. …… ni le fa oran dida. A. Oju kokokro B. Iwa omoluwabi C. akikanju.

    APA KEJI

  1. Ko apeere oran dida mefa sile.
  2. Ko asa marun-un sile ninu iwe apileko ti ijoba yan ki o si salaye meji ninu asa naa.

     
     
     

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *