OSE KEWAA
LETA GBEFE KIKO
AKOONU
Leta gbefe-;ni leta ti a ko si eniyan ti a mo dunju bii obi, ore ,ebi ,egbon, aburo,ara ile eni tabi eniyan miiran ti a mo ri.
Ninu leta gbefe, a le da apara tabi se efe ti o ba wu wa.
Ilana fun leta gbefe kiko
Ti a ba fe ko leta gbefe, eyi ni awon igbese ti a gbodo tele nigba ti a ba fe ko o
(i) Kiko adiresi akoleta-;eyi yoo wa ni apa otun ni oke iwe.
                Muslim Grammar School,
                P. O.Box 224,
                Eko.
                21st March 2011.

 (ii) Deeti kiko-; ila ti o tele adiresi ni a maa n ko deeti si.
(iii) Ikini-;owo osi ni ibere ila ti o tele deeti ni a n ko ikini si pelu ami koma ni ipar.-     baba mi tooto,Egbon mi owon,Aduke mi atata abbl.
(iv) Inu leta-;ibi yii gan-an ni a o ti soro lori idi ti a fi n ko leta
    -“idi pataki ti mo fi n ko iwe yii si yin ni wi pe”………..
(v) Ikadii-; Owo otun pepa ni a o o sun owo si lati dagbere pelu ami koma ni ipari.
                Emi ni tire ni tooto,
(vi) Oruko akoleta-;oruko abiso nikan ni akoleta gbodo ko pelu ami idanuduro.
            Kola.
            Fadeke.
    
IWE AKATILEWA
Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, Asa Ati Litireso fun ile Sekondiri Agba S.S. 3. Corpromutt Publihers Nig Ltd Oju iwe 35-45.

         ASA
OKU SISE
– SISE ORO OKU.
     AKOONU
        Oku sise-;ni imojuto oro ile pelu ipese ohun jije ati ohun mimu ti awon eniyan oku olomo tabi oku agba maa n se fun oku ati awon a-bani-saajo ti o waa ki won ni ile oku.
Bi oku tile je odokunrin ti o ba ti ni omo nile,oku sise yoo wa bi ko tile ni koja akara dindin gege bi saraa fun oku.Ara etutu ki ona oku o le la gaaraga lo si ajule orun ni awon Yoruba ka oku sise si.
Fun oku ayo,oku agba,oku arugbo,eto oku sise repete lo wa ninu asa Yoruba.Bi owo po lowo awon omo olooku nigba naa won ni lati lo wa owo ya ki asiri won o le bo lori sise eyin baba tabi iya.
    Laye atijo odidi ojo meje, mesan-an tabi ju bee lo ni ariya oku sise maa n gba ni ile oku agba.Awon okorin yoo maa ki oriki oku,awon onilu yoo si maaa sise owo won.
Ni ojo isinku; Akara didin ni awon omolooku yoo pese lopolopo fun awon eniyan lati aaro di ale.
Ni ojo keji isinku; akara dindin naa ni yoo gba gbogbo ile oku kan.
Ni ojo keta isinku abbl.; Awon omo olooku yoo kita; eyi nip e won o se eto ariya ojo keta.Ojo yii ni ipese jije ati mimu yoo bere ni pereu,eran pipa,obe sise lorisiirisii,oka riro,iyan gigun abbl. Ni yoo wa ni ki ounje le kari gbogbo eni ti o wa ati gbogbo eni ti omolooku ni lati gbe ounje ranse si ni aarin ilu..Awon onilu paapaa naa yoo maa lulu kikankikan ni agboole oku; ipese ounje ati mimu yoo wa fun awon naa.
    Bee ni awon omolokuu ni lati se eto ariya yii ni ojo kerin titi di ojo kesan-an,sugbon eyi ti o wopo julo ni ki awon oku o kije lati pari oku sise,eyi nip e eto ariya ojo keje mu oku sise naa dopin.
Ni ojo kejidinlogun isinku ni eto yiyo ese oku agba obinrin kuro ni nu ebi

 IGBELEWON
Salaye awon koko ti o ro mo oku sise
Ise Asetilewa
1.Leta ——— ni a maa n ko si ore,ara,ebi ati ojulumo.
(a) eni mimo (b) gbefe (d) aigbagbefe
2.Adiresi meloo ni leta si ore wa maa n ni?
(a) kan (b) meji (d) meta.
3———- ni ewi atenudenu ti awon ode maa n lo lati dagbere fun ode egbe won.
(a)oku pipe (b) igbala (d) iremoje.         
4.Okan lara ohun ti o maa n jeyo ninu oku pipe re ni ———
(a)oriki oku (b) iwa re (d) iye ile ti o ko.         
5.ojo——— isinku ni won maa n yo ese obinrin agba kuro ninu ebi.
(a) keta (b) kejidinlogun (d) kejidinlogbon.

             Apa keji
1.Ko leta si ore re,ki o si salaye fun un nipa ile-iwe re titun ti o wa bayii.
2.Daruko awon ewi atenudenu ti a n lo fun oku pipe.
b.Salaye koko ti o maa n je jade ninu won pelu apeere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *