ILANA ISE FUN SAA KETA FUN OLODUN KEJI (JSS TWO)
OSE KIN-IN-NI:
EDE: ATUNYEWEO ISE SAA KEJI

  • AROKO ALAPEJUWE/ONIROYIN


ASA:

ATUNYEWO IWA OMOLUABI

LITIRESO
: ATUNYEWO ISE SAA KEJI: EWI ALOHUN TO JE
MO ESIN IBILE BII; IJALA, IYERE IFA,
IWI EGUNGUN, abbl

OSE KEJI: EDE: LETA GBEFE

  • AWON WO NI A N KO O SI
  • AWON IGBESE INU LETA GBEFE
  • ORI ORO TO JE MO LETA GBEFE


ASA
: IGBAGBO
YORUBA NIPA OLODUMARE
     LITIRESO: EWI ALOHUN TI A N FI ORO INU WON DA
WON MO
OSE KETA: EDE: APOLA ORUKO
ATI ISE RE

ASA: IGBAGBO ATI ERO YORUBA NIPA ORISA

LITIRESO
: KIKA IWE LITIRESO APILEKO TI IJOBA YAN- EWI
OSE KERIN:
EDE: APOLA ISE , ISE ATI IHUN RE

ASA: BI AWON AKONI EDA SE DI ORISA

LITIRESO
: KIKA IWE LITIRESO TI IJOBA YAN
OSE KARUN-UN:
EDE: ISEDA

ORO ORUKO

  • NIPA LILO AFOMO IBERE
  • NIPA LILO AFOMO AARIM


ASA
: ASA IKINI NI ILE YORUBA

LITIRESO: KIKA IWE TI IJOBA YA
OSE KEFA: EDE: ISEDA ORO ORUKO NIPA LILO APETUNPE

ASA
: IGBAGBO YORUBA NIPA IYE LEYIN IKU

LITIRESO
: EWI ALOHUN TI A FI ORO INU WON DA WON MO
OSE KEJE: EDE: LETA AIGBEFE

ASA : AWON OHUN MIMO NINU ESIN IBILE

EDE: ATUNYEWO AMI OHUN
OSE KEJO:
EDE: AWE GBOLOHUN EDE YORUBA

LITIRESO
: KIKA IWE EWI TI IJOBA YAN
OSE KESAN-AN:
ASA: ASA ISINKUN NI ILE YORUBA

LITIRESO:
KIKA IWE EWI TI IJOBA YAN
OSE KEWAA: EDE: IHUN APOLA APONLE ATI ISE TO N SE
NINU GBOLOHUN

ASA: OWE ILE YORUBA

LITIRESO
: KIKA IWE EWI TI IJOBA YAN

 OSE KOKANLA ATI IKEJILA: EDE: ATUNYEWO EKO
LORI ISEDA
ORO
ORUKO

ASA:
ATUNYEWO ASA IKINI NI ILE YORUBA

LITIRESO:
ATUPALE IWE EWI TI A KA

OSE KIN-IN-NI
EKA ISE: EDE
ORI ORO: AROKO ALAPEJUWE
Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re .
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se apejuwe eniyan, nnkan tabi bi ayeye se ri
gan-an.
ILANA TO SE PATAKI FUN AROKO ALAPEJUWE

  1. Yiyan ori oro
  2. Sise arojinle ero lai fi kan bokan ninu
  3. Sise apejuwe ero leseese sin iwe ni ipin afo(paragraph) kookan

     

ORI ORO TO JE MO AROKO ALAPEJUWE

  1. Ile iwe mi
  2. Ounje ti mo feran
  3. Ijamba oko kan ti o sele loju mi abbl.

     
     AROKO ASOTAN /ONIROYIN(NARATIVE ESSAY)
    Aroko oniroyin ni arokko ti a fi n so nipa isele ti a fi oju war i tabi awon isele ti a gbo lenu enikan
    ILANA FUN KIKO AROKO ONIROYIN

    1. Koko oro
    2. Ero: akekoo gbodo ni ero kan lokan nipa ori oro ti o fe soro le
    3. Eto: Agbekale aroko gbodo wan i sise-n-tele
    4. Ilo ede:Akekoo gbodo se amulo ilo ede bii; owe, akanlo ede, akoto, ifamisi ori oro, ati ona ede lorisirisi
    5. Igunle: eyi ni ipari aroko.awon akekoo yoo soro soki lori aero won nipa ori oro aroko ti won ko.

       APEERE ORI ORO AROKO ASOTAN/ONIROYIN

      1. Ayeye ere onile-jile ti o koja ni ile iwe mi
      2. Ere boolu alafesegba kan ti mow o
      3. Ijamba oko kan ti o sele ni osodi
      4. Isomoloruko omo egbon mi obinrin

IGBELEWON:

  • Fun aroko ni oriki
  • Kin ni aroko asapejuwe ati asotan?
  • Salaye awon ilana fun kiko awon aroko wonyi
  • Ko ori oro to jemo aroko asotan ati asapejuwe

ISE ASETILEWA:

  • Ko aroko lori ayeye onile-jile ti o koja ni ile iwe re

 ASA: IWA OMOLUABI
Omoluabi ni omo ti a bi ti a ko, ti o si gba eko rere.
Ise ati ise omoluabi bere lati inu ile ti a ti bi i
Die lara Ojuse omoluabi ni awujo

  • Iwa ikini
  • Ooto siso
  • Iwa irele
  • Iwa suuru
  • Bibowo ati iteriba fun agba
  • Iwa igbonran

     

Pataki iwa omoluabi

  • O maa n fi iru eni ti eniyan je han nitori eefin ni iwa
  • O maa n buyi kun ni
  • O maa n je ki a ma iru idile ti eniyan ti wa
  • O n je ki eniyan tojo

IGBELEWON:

  • Fun iwa omoluabi loriki
  • Ko iwa omoluabi marun-un
  • Salaye Pataki iwa omoluabi ni ile Yoruba

ISE ASETILEWA:

  • Salaye iwa omoluabi meji pelu apeere

 
 LITIRESO: AWON EWI ALOHUN AJEMO ESIN IBILE ATI ORISA TI A N LO
WON FUN:

  Ewi Orisa

  1. Esa-pipe egungun
  2. Esu-pipe esu
  3. Sango-pipe sango
  4. Oya-pipe oya
  5. Ijala sisun ogun
  6. Iyere-ifa orunmila
  7. Orin arungbe oro

     

IGBELEWON:

  • Ko orisa ile Yoruba ati esin to room okookan won

ISE ASETILEWA:
Orisa wo lo romo awon esin wonyi:

  • Esa-pipe
  • Orin arungbe
  • Iyere-ifa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *