OSE KESAN-AN
Akoole Ise: Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi
Salako:-    Kerekere odun 2015 n ko gba wole
Adunni:-    Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re
Alake:-        Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun
Salami :-    Awon awako n sare asa pajude loju popo ni asiko yi o
Adunmi :-    Bi o se emi ati ile mi, buburu kan ko ni subu lu wa o
Alake :-    Adura re dara sugbon oni-mo taara eni nikan ni o ore mi —– (erin po)
Salako :-    Ati awa ati ebi wa a ko ni fi wa rubo odun 2015 (Amin)
Alake :-    Amin o —–
Salami :-    Alake, jowo bi e ba ti n lo, e ki lo fun awako yii ki o maa sare aspajude o
Alake:-        o seun salami, edumare yo so ipade wa o.
Aduni:-    Ri daju pe o mu ebun odun wa fun omi ore re Pataki bi o ba ti de
Salako:-    Odun a yabo fun gbogbo wa
Salami:-    Amin
Alake:-        E yin ore e ki le o

 Igblewon:-

  1. Yabo ninu ayoka yin tumo si _________________
  2. Ta ni o n rin irin ajo ?
  3. Awon wo ni o n sare asapejude loju popo ?

 Ise Asetilewa :-

  1. Ore meloo ni o wa ninu ayoka oke yii ? (a) mefa (b) meji (d) marin
  2. Ilu ________ ni alake n lo (a) ebonyi (b) Ibadan (d) idonre
  3. Ta ni onimo-taara-eni-nkan ? (a) salako (b) salami (d) adunni
  4. ___________ ko wo aago enikeni se ijoba re (a) Olodumare (b) oluko (d) aare Buhari
  5. Akole ti o ba ayoka yii mu ni ___________ (a) ore mi (b) ore asapejude (d) odun wole de

ASA:- Iwa Omoluabi
Omoluabi ni omo ti a bi ti a si ko ti o gba eko rere.
Ise ati iwa omoluabi bere lati inu ile ti a ti bii
OJUSE OMOLUABI NI AWUJO

  1. Iwa ikini
  2. Bibowo ati iteriba fun agba
  3. Ooto siso
  4. Iwa irele
  5. Iwa suuru
  6. Iwa igboran
  7. Iwa pele lawujo
  8. Fi fi ife han si omonikeji

PATAKI IWA OMOLUABI

  1. O maa n fi iru eni ti eniyan je han nitori eefin ni iwa
  2. O n buyi kun ni
  3. O n je ki eniyan tojo (pe laye)
  4. O maa n je ki a mo iru idile ti eniyan ti wa abbl.

 Igbelewon :-

  1. Fun omoluabi loriki
  2. Ko ojuse omoluabi marun-un
  3. Salaye ise pataki iwa omoluabi lawujo

 Ise Asetilewa : yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) Oju Iwe ketalelogbon Eko kokandinlogun

 LITERSO :- Kika Iwe Apileko ti Ijoba Yan.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *