ISE-:EDE YORUBA                 CLASS: S.S.S.2
ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KETA
Ose:

  1. EDE:    Aroko ti o je mo isipaya.

ASA:    EkoIle
LIT:    Itupale Asayan iwe litireso ti ijoba yan. WAEC/NECO.

  1. EDE:    Silebu Ede Yoruba.

    ASA:    Isse abinibi. Ise Agbe.
    LIT: Itesiwaju lori Asayan iwe litireso ti ijoba yan. Eda Itan. Ibudo Itan.

  2. EDE:    Aroko Onisorogbesi

    ASA:    Ona Ibaranisoro.
    LIT:    Itupale Iwe Litireso.

  3. EDE:    Ihun Oro. Iseda Oro Oruko.

    ASA:    Itesiwaju eko lori ona Ibaranisoro.
    LIT:    Sise atupale asayan iwwe ti Ijoba yan.

  4. EDE:    Onka Yoruba.

    ASA:    Awon orisa Ile Yoruba. Ogun, Obatala ati Esu.
    LIT:    Kika awon iwe asayan ti ijoba yan.

  5. EDE:    Onka Yoruba.

    ASA:    Awon orisa ile yoruba ati bi a se n bo won. Orunmila ati Sango. Oriki won.
    LIT:    Kika awon iwe asayan ti ijoba yan.

  6. EDE:    Atunyewo awon eya ara ifo.

    ASA:    Awon Orisa ati bi a ti n bo won. Awon orisa miiran ni agbegbe akekoo. Ipo
    won orisa ni ile Yoruba.
    LIT:    Kika awon iwe asayan ti ijoba yan.

  7. EDE:    awon iro ninu ede Yoruba.

    ASA:    Ero ati igbagbo awon Yoruba lori Oso ati Aje.
    LIT:    Kika awon iwe asayan ti ijoba yan.

  8. EDE:    Atunyewo iro Konsonanti ati iro faweli lo kookan.

    ASA:    Ero ati igbagbo awon Yoruba akudaaya ati abami eda.
    LIT:    Kika awon iwe asayan ti ijoba yan.

  9. EDE:    Atunyewo eko lori ami ohun.

    ASA:    Igbagbo awon yoruba nipa Ori ati eledaa.
    LIT:    Kika awon iwe asayan ti ijoba yan.

  10. & 12 EDE:    Idanwo ati ipari saa keta lori Ede, Asa ati Litireso.

    IWE ITOKASI

  11. Imo, Ede, Asa Ati Litireso. S.Y Adewoyin
  12. Eto Iro ati Girama fun Sekondiri Agba. Folarin Olatubosun.
  13. Akojopo Alo Apagbe: Amoo A. (WAEC).
  14. Oriki Orile Metadinlogbon: Babalola, A (WAEC).
  15. Iremoje Ere Isipa Ode: Ajuwon B. (WAEC).
  16. Igbeyin Lalayonta: Ajewole O. (WAEC).
  17. Iya Atata: Fadiya, O. (WAEC).
  18. Ore Mi: Aderibigbe, M. (WAEC).
  19. Egun Ori Ikunle: Lasunkanmi Tela. (NECO).
  20. Omo Ti A Fise Wo: Ojukorola Oluwadamilare. (NECO).
  21. Ewi Igbalode: Taiwo Olunlade. (NECO).

     
     OSE KIN-IN-NI

 AROKO AJEMO ISIPAYA
Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni:

  1. Ise Tisa
  2. Oge Seise.
  3. Aso Ebi
  4. Imototo.
  5. Ise ti mo fe lojo iwaju.

Ki a to le ko akoyawo lori okookan ori-oro wonyi, a gbodo ni arojnle ohun ti won je, itumo ati itumo won miiran to farasin tabi ohun ti o ni abuda won. A nila ti wo anfaani ati aleebu ki a si fi arojinle ero gbe won kale.

 IGBELEWON: ko aroko lori Oge sise tabi omi.

 Iwe Akatilewa:
Adewoyin S.Y (2014) IMO, EDE, ASA ATI LITIRESO YORUBA fun ile eko girama agba S.S.1 Corpromutt Publisher Nig Ltd. O.I 155-156.

 EKO ILE
Eko ile Yoruba, awon eko ti awon obi maa n ko omo lati kekere ni a n pe ni eko-ile. Yoruba ni ‘ni ile lati ko eso rode’. Awon eko bee ni ikini, imototo, isora, iwa ti o to si obi, agbalagba, alejo ati alagbe eni. Omo ti won ko to si gba, ti o sin mu eko naa lo nigba gbogbo ni a n pe ni omoluabi. ‘omo-olu-iwa-bi. Olu iwa ni eni ti o je orison gbogbo iwa rere. Abuda omoluabi ni =w=, iteriba, ise sise, oninuure, onisuuru, eni ti ko huwa abosi tabi ireje si eni keji. ABIIKO ati AKOOGBA.
IGBELEWON:

  1. Ta ni oluko eko ile.
  2. Ko abuda omoluabi marun-un miiran.
  3. Salaye abiiko ati akoogba.
  4. Pa owe merin ti o je mo eko ile.

 Iwe Akatilewa::
Adewoyin S.Y (2014) IMO, EDE, ASA ATI LITIRESO YORUBA fun ile eko girama agba S.S.2 Corpromutt Publisher Nig Ltd. O.I 129-135.

 ATUPALE IWE ASAYAN

 Atupale iwe asayan ti ijoba yan.

 APAPO IGBELEWON:

  1. ko aroko lori Oge sise tabi omi.
  2. Ta ni oluko eko ile.
  3. Ko abuda omoluabi marun-un miiran.
  4. Salaye abiiko ati akoogba.
  5. Pa owe merin ti o je mo eko ile.

 ISE ASETILEWA

  1. Aroko ti o je mo isipaya ni (a) ile iwe mi (b) baba mi (c) ilu Ibadan (d) eran osin.
  2. Ewo ni ki i se ara won? (a) ise tisa (b) ojo ti n ko le gbagbe (c) obe egusi (d) omi.
  3. Awon ti o koko maa n ko omo ni eko ile ni (a) egbon eni (b) iya (c) iya ati baba (d) ara adugbo.
  4. ‘owu ti iya gbon ni omo yoo ran’ owe yii tumo si wi pe (a) ise ti baba ba se ku ni omo maa se (b) ise ti iya ba se ku ni omo maa se (c) iwa omo maa n jo ti iya re (d) omo maa n ran aso iya re.
  5. Eda ita ni (a) awon onkorin (b) osere (c) awon ti won kopa ninu iwe ati ere (d) awon ti o ko itan.

     APA KEJI

  6. Ko aroko lori iyan
  7. Ko iwa omoluabi merin sile
  8. Salaye akanlo-ede ayaworan merin.

     

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *