OSE KETA (DISCRIPTIVE ESSAY)
Akole Ise: Ede – Aroko Alapejuwe
Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.
Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe

  1. Ile iwe mi
  2. Ilu mi
  3. Oja ilu mi
  4. Ounje ti mo feran
  5. Ile isin wa
  6. Ijanba oko kan ti o sele loju mi abbl.

Ilana to se Pataki fun aroko asapejuwe

  1. Yiyan ori oro
  2. Sise arojinle ero lai fi kan bokan ninu
  3. Sise apejuwe oro la see se sinu iwe ni ipin afo (paragraph) kookna.

 Igbelewon :

  1. Kin ni aroko
  2. Fun aroko asepejuwe ni oriki
  3. Ko ori ora aroko asapejuwe marun-un

 Ise asetilewa:-yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) Oju Iwe ketadinlogbon Eko kerinla

 ASA:- Asa Iran-ra-eni lowo ni ile Yoruba
Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba e ni asiko pipe.
Ona iranra-eni lowo ni aye atijo eti ni ode oni ni wonyi :-

  1. Esusu
  2. Ajo
  3. Awe
  4. Aaro
  5. Arokodoko
  6. Egbe alafowosowopo

Igbelewon :

  1. Salaye asa irara-eni lowo
  2. So iyato to wa laarin awon wonyi
    1. Esusu ati ajo
    2. Owe ati aaro

 Ise asetilewa:- yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) Oju Iwe kokandinlogbon Eko kerindinlogun

 LITIRESO:- IWE KIKA – ERE ONISE

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *