ISE: EDE YORUBA S.S.S.2
ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KEJI
OSE
1. EDE: Aroko Onileta (Leta Gbefe ati Leta Aigbagbefe).
ASA: Isinku ni ile Yoruba 1: orisii bi iku se n pani ( ijamba, aisan), itufo ati itoju oku ibanikedun ati sise oku agba.
LIT: Asayan iwe litireso ti ajo WAEC/NECO yan ti egbe akomolede ipinle Eko fowosi.
2. EDE: Aayan Ogbufo- titumo ewi ede geesi si ede Yoruba, Awon ofin to romo aayan ogbufo.
ASA: Isinku ni ile Yoruba 1: orisii oku ati bi a se n sin won, oku riro ati etutu oku sise bi ti eleegun
LIT: Itupale lori iwe Litireso ti Ajo WAEC/NECO yan fun S.S.S.2. Eda itan, ibudo itan.
3. EDE: Aayan Ogbufo wuuru titumo eyo oro gbolohun ede geesi si ede Yoruba.
ASA: Eto ogun jije I: oriki, iyato laarin ogun baba ati ogun iya, ona ti a n gba pin ogun, awon ti o ni eto si ogun pinpin, aleebu ti o romo ogun pinpin.
LIT: Itupale iwe litireso: ahunpo itan ati asa Yoruba to suyo ninu itan naa.
4. EDE: Aroko Onileta (Leta Aigbagbefe). Igbese, adiresi, Deeti, Akole, Koko oro, Ikadi, oruko ati ifowosi.
ASA: Eto ogun pinpin II. Ipa ofin ijoba lori ogun laye ode oni.
LIT: Sise itupale asayan iwe litireso: ilo ede ati akanlo ede, sise orinkinniwin won.
5. EDE: Iparoje ati Isunki. Pipa Iro je ninu Iso Isunki to waye, Awon Ihun ti ipaje ti
le waye. Dida Awon Oro tabi Iso ti Isunki ti le waye.
ASA: Eto idajo laye atijo: Ona ti a n gba se idajo laye atijo, ipa ti emese/ilari n ko ninu eto idajo.
LIT: Asayan iwe litireso ti ajo WAEC/NECO yan ti egbe akomolede ipinle Eko fowosi.
6. EDE: Aranmo
ASA: Eto idajo lode oni.
LIT: Asayan iwe litireso ti ajo WAEC/NECO yan ti egbe akomolede ipinle Eko
7. EDE: Oro Agbaso
ASA: Aroko pipa.
LIT: Kika iwe litireso ti ijoba yan.
8. EDE: Oro/Gbolohun Oniponna.
ASA: Eewo nile Yoruba.
LIT: Kika iwe litireso ti ijoba yan.
9. EDE: Awe gbolohun ede Yoruba.
ASA: Igbagbo ati ero Yoruba nipa ajinde leyin iku.
LIT: Awon eka ede Yoruba.
10. EDE: Apola ninu gbolohun ede Yoruba: apola oruko, oro ise, ihun apola, isori oro ti a le
ba labe apola ise ati apola oruko.
ASA: Igbagbo Yoruba nipa Olodumare
LIT: Kika iwe ti ijoba yan
11. Atunyewo lori gbogbo ise saa yii.
*W# *T_KAS&
- Oy4bqmj7 Mustapha (2006) @K_ $D$ YOR^BQ TITUN Iwe kej8 University Press Plc.
- Ay= Bqmgb9s3 (1990) FON_L_J* $D$ YOR^BQ University Press.
- Ad3w[yin S.Y (2006) *M+, $D$, ZXZ zti L&T&R#S+ Ile 2k- Sekondiri Zgbz. Copromutt Publishers.
- Zm=-, A. Zk9j[p= Zl- Zpav4: (WAEC).
- Babal[lq, A.
Or7k8 Or7l2 M1tzd7nl-v=n: (WAEC). - Zj6w=n, B.
*r4m=j3 Er3 *s7pq {dc: (WAEC). - Aj3w[l3, O.
*v2y8n Lalqy0nta: (WAEC). - Fqd7yz, O.
*yq Ztztz: (WAEC). - Ad3r7bigb3, M. +r1 Mi: (WAEC).
- Lqs5nkznm8 T2lz. $g5n Or7 *k5nl2: (NECO).
- Oj5k0r-lq Ol5wadqmilqre. {m[ T7 A F8s1 W0: (NECO).
- Tq8w0 Ol5nlqd3. Ew8 *gbzl9d3: (NECO).
OSE KIN-IN-NI
EDE
AROKO ONILETA
AKOONU
Orisii leta meji lo wa ninu ede Yoruba, awon naa ni:
Leta Gbefe ati
Leta Aigbagbefe.
Leta mejeeji ni o ni eto ati ilana ti a n gba ko won.
Leta gbefe ni leta ti a ko si obi, ara, ore, ebi, egbon, aburo tabi si eni ti a mo ri.
ILANA LETA GBEFE NI
- kiko adiresi eni ti a ko leta si. (Eyi le je olooro tabi elebe ni owo otun oke leta naa).
- Deeti
- Ibere leta pelu ikini ibere. (Tunji bawo, Aunti mi, Baba mi owon, Mama mi owon. ikini ni o maa n bere leta.a le wi pe ‘ se alaafia ni o wa ati gbogbo ara ile.
- Inu leta.
- Ni ipari leta gbefe, a o dagbere fun eni ti a ko leta si pelu.apeere; – ire o, o digba. ‘ tire ni tooto’.
- Oruko eni ti o ko leta ni o maa n gbeyin. Apeere Kola, Bolu, Tope, Seun.
Ninu leta gbefe aaye wa fun ikini, apara ati awada.
LETA AIGBAGBEFE.
Eyi ni leta ti a ko si ile-ise ijoba bii ile-ise amohun-maworan,ile-ise itewe,yunifasiti abbl.
Ninu leta aigbagbefe eni ti o di ipo kan mu ni a maa n ko leta si ki I se enikan ni pato.
- ko si pe a n ki ni, sere tabi se awada ninu leta aigbagbefe ibi koko leta ni a maa n lo taara.
- Adiresi meji ni o maa n wa ninu leta aigbagbefe,adiresi eni ti o ko leta ati eni ti a n ko leta si.A maa n mo ipo eni ti a n ko leta si.apeere,alaga,akowe,oga agba.
- Ori-oro tabi akole maa n wa ninu leta aigbagbefe.
- Inu leta/koko ti a fe bog an-an ni a gbodo lo taara.
- Ipari leta. ’emi ni tiyin ni a gbodo fi pari.
- Oruko eni ti o ko leta. Apeere:
LETA AIGBAGBEFE.
12 Adeoti street,
Oyo,
23rd may,1996.
The Director,
Iwe Iroyin Yoruba press,
77, Kadara Street,
Lagos.
Olootu
IBEERE FUN IPO AKOWE ATEWE.
Koko inu leta.
Emi ni tiyin
Adebisi Raheem.
IGBELEWON:
Salaye iyato to wa laarin leta gbefe ati aigbagbefe
IWE ITOKASI
Adewoyin S.Y (2006) Imo,Ede, Asa ati Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. (S.S.S.3) Oju iwe 1-35 Corpromutt (Publishers) Nigeria Ltd.
Deeti …………………
ETO ENI SI OGUN JIJE
- Oriki
- Ohun ti a n je logun
- Ona ti a n gba pin Ogun
- Opo Sisu ati Omo Ajemogun
- Ire ati Ibi to ro mo Ogun Pipin
- Iyato laarin Ogun Iya ati Baba
AKOONU
Ogun ni gbogbo dukia ti oloogbe fi sile fun omo ati awon ebi. Adura gbogbo obi ni pe ki won ri omo rere gbeyin won.
Oro ogun pipin yii gbelege pupo ni pataki julo, ogun baba lo gbelege julo nitori opolopo iyawo ti won maa n ni laye atijo. Baba – n – sinku ni o ni ase lori isinku ati ogun pipin
Awon ohun ti won maa n pin logun. Gbogbo ohun ti oku ni ni dukia. Bii
- Ile
- Ile
- Oko
- Iso
- Iyawo
Gbogbo awon nnkan wonyi ni won maa n pin logun. Obinrin (Iyawo) ti oku fi sile naa ni a le su lopo fun aburo tabi molebi oku ti o ba kan-an gbongbon.
ONA TI A N GBA PIN OGUN
Ona meji ni won n gba pin ogun ni aye atijo. i. ori –o- jori ati ii.idi igi.
ORI- O-JORI -: eyi tumo si pe ogun ti oloogbe ba fi sile ni won yoo pin ni deede fun gbogbo omo ti o bi.
IDI IGI-: bi oku ba ku laye atijo, ti o si ni iyawo pupo. Idi igi ni won fi maa n pin ogun bee. Iyawo to bi omo kan ati olomo mejo ogun kan naa ni won yoo pin fun awon mejeeji. Ireje maa n wa ninu ogun pipun. idi niyi ti ogun baba si fi lewu pupo nitori pe inu olomo mejo ko le dun si ogun ti won pin fun-un, koda won maa n se orogun si ara won lori ogun.
Iyato laarin ogun iya ati baba. Ogun iya lo fi okan bale julo nitori pe ko si orogun ninu ogun iya. idi niyi ti won fi n paa lowe pe – “Gbede bi ogun iya, anini lara ba ogun baba”.
Igbelewon
1a Kin ni ogun pinpin
b. Daruko awon ohun ti a n je logun.
Iwe Akatilewa
Imo Ede Asa ati Litireso SS3 o.i 200-203
Adakedajo.
APAPO IGBELEWON
1a Kin ni ogun pinpin
b. Daruko awon ohun ti a n je logun.
2. Salaye iyato to wa laarin leta gbefe ati aigbagbefe
ZT%NY@W) IX!
- Ko eya ara ifo mejo sile.
- Ko eya ara ifo afojuri mefa sile.
- Ko eya ara ifo aifojuri mefa sile.
ISE ASETILEWA
- Leta ti o maa n ni adiresi meji ni leta A. gbefe B. aigbefe C. asotan D. asapejuwe
- Leta ti a maa n bu owo lu ipari re ni A. gbefe B. aigbefe C. asotan D. asapejuwe
- ….. ni a maa n ko eni ti o sun mo wa A. gbefe B. aigbefe C. asotan D. asapejuwe
- Eni ti won maa n pe ni eni orisa ni A. eniyan dudu B. eni giga C. afin D. afinju
- ….. n sunkun oku akasoleri n sunkun ara won A. eniyan B. ara orun C. oku D. eni maa ku.
APA KEJI
- Salaye bi won se n sin:
- Adete
- Abuke
- Agba ode
- Eni ti Sango pa.