{"id":4121,"date":"2023-10-06T09:48:03","date_gmt":"2023-10-06T09:48:03","guid":{"rendered":"http:\/\/localhost\/ecole9ja\/?p=4121"},"modified":"2023-10-06T09:52:13","modified_gmt":"2023-10-06T09:52:13","slug":"week-3-ss3-second-term-yoruba-notes","status":"publish","type":"post","link":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/posts\/week-3-ss3-second-term-yoruba-notes\/","title":{"rendered":"Week 3 &#8211; SS3 Second Term Yoruba Notes"},"content":{"rendered":"<p>\u00a0<strong>OSE KETA<br \/>\n<\/strong>ORO \u2013 AYALO.<br \/>\nInu ede ti a ti n ya oro lo.<br \/>\nOna ti a n gba ya oro wonu ede Yoruba.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>Akoonu<\/strong><br \/>\n\tOro \u2013 ayalo -: ni awon oro ajeji ti a maa n ya wonu ede Yoruba lati inu ede miiran<br \/>\nOro \u2013 ayalo -: ni mimu oro lati inu ede kan wo inu ede miiran lona ti pipe ati kiko re yoo fi wa ni ibamu pelu ede ti a mu-un wo.<br \/>\nOro \u2013 ayalo maa n mu ki ede dagba.<br \/>\nBakan naa, o maa n je ki oruko wa fun awon nnkan ati ero tuntun ti o ba n sese n wo awujo wa<\/p>\n<p>\u00a0Yoruba ni ilana meji ti won n gba ya oro wo inu ede Yoruba, awon naa ni<br \/>\n&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Ilana afetiya<br \/>\n&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 ilana afojuya<br \/>\nIlana afetiya -: eyi ni pipe oro ayalo ni ona to sunmo bi awon elede se n pe oro gan-an<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\nBible &#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Baibu<br \/>\nPeter\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Pita<br \/>\nTable\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Tebu<br \/>\nEsther &#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0          \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Esita<br \/>\nDeacon &#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Dikin<br \/>\nCouncil &#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0kansu<br \/>\nAl- basal &#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0alubosa<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0Ilana afojuya :- eyi ni kiko oro ni liana eyi to sunmo bi awon elede se n ko.awon elede se n saaba maa n lo ilana yii<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0Soldier\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 &#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0soja<br \/>\nTable  \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0tabili<br \/>\nPeter \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0peteru<br \/>\nEsther \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0esiteri<br \/>\nBible \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Bibeli<br \/>\nDeacon \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Diakoni<br \/>\nParadise \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0paradise<br \/>\nHebrew \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Heberu\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<\/p>\n<p>\u00a0Inu awon ede wonyii ni a ti n ya oro wo inu ede Yoruba<br \/>\n     Ede  Geesi<br \/>\n     Ede  Larubawa<br \/>\n     Ede  Faranse<\/p>\n<p>\u00a0Bi oro ayalo se wonu ede Yoruba<br \/>\nEyi ni orisirisii ona ti oro ayalo gba wonu ede Yoruba <\/p>\n<ol>\n<li>Esin:-  nipase esin musulumi ati esin Kristi ti won mu wa fun wa ni a se ni awon oro wonyi:  mosalasi, soosi, alijanna, angeli bibeli, pasito, kurani abbl\n<\/li>\n<li>Ajose owo:- eyi ni ajose owo laarin Yoruba ati awon eya miiran ap:  senji, korensi, wisiki, buluu\n<\/li>\n<li>Eto iselu:- Nipase ijoba ajeji ti awon larubawa ati Geesi mu wa ni a ti ya opolopo oro bii seria, kootu, sinato\n<\/li>\n<li>Asa ati olaju:- ajumose nipa asa ati olaju mu ki a ya opolopo oro lo ap:  yigi, marede\n<\/li>\n<li>\n<div> Eto eko:- eyi ni oro ti a ya nipa eto eko ap tisa, boodu,\n<\/div>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0AWON IRO TI A FI N SE AARO ARA WON<br \/>\nKi oro ede Geesi ti a ya lo to le di ara oro mu ede Yoruba, o gbodo tele ofin ede Yoruba\n<\/li>\n<li>\n<div>Konsonanti ki i gbeyin oro ninu   ede Yoruba bi oro ayalo ba ni, a o fi faweli ti o ye seyin re, o le je: i, u \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0a tabi o, ap\n<\/div>\n<p>Bread \u2013 buredi<br \/>\nGum \u2013 goomu<br \/>\nBed \u2013 beedi<br \/>\nShirt \u2013 seeti<br \/>\nfail \u2013 feeli<br \/>\nGlass \u2013 gilaasi<br \/>\nGold \u2013 goolu<\/p>\n<p>\u00a0ii.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Yiyo konsonanti ipari oro ayalo kuro ap<br \/>\nMobil \u2013 mobi<br \/>\nMoses \u2013 mose<br \/>\nJesus \u2013 jesu<br \/>\nLazarus \u2013 lasaru<\/p>\n<p>\u00a0iii.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Yiya isupo konsonanti oro- ayalo fifi faweli ya isupo konsonanti ap<br \/>\nbread \u2013 buredi<br \/>\nmilk \u2013 miliiki<br \/>\niray \u2013 Tiree<br \/>\nstation \u2013 Tesan<br \/>\nbelt \u2013 beliiti<\/p>\n<p>\u00a0iv.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Ifiropo konsonanti ninu oro ayalo Nigba miirran konsonanti oro Geesi maa n yato si ti Yoruba ap:<br \/>\nLazarus \u2013 lasaru<br \/>\nChurch \u2013 soosi<br \/>\nQueen \u2013 kun-yin<br \/>\nValve \u2013 faafu<br \/>\nStamp \u2013 sitanbu<br \/>\nCup \u2013 koobu<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<\/li>\n<\/ol>\n<ul>\n<li> Ami gbodo wa lori oro- ayalo\n<\/li>\n<li>Oro ayalo lo maa n bere pelu ami ohun oke\n<\/li>\n<li>Faweli aranmupe maa n bere oro ayalo\n<\/li>\n<li>Iwulo  oro ayalo\n<\/li>\n<li>Oro ayalo lo maa n mu ki edi dagba\n<\/li>\n<li>\n<div>Nipa yiya oro lo a maa n ri oruko fun awon nnkan ati ero tuntun ti o ba sese n wo awujo wa.\n<\/div>\n<p>Ofin ti o de oro ayalo<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IGBELEWON<br \/>\n<\/strong>1. Kin ni  oro-ayalo?<br \/>\nOna meloo ni a n gba lati ya oro lo? Salaye won pelu apeere<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IWE AKATILEWA<\/strong><br \/>\n\t\t\tAewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>ASA<br \/>\n<\/strong>AWON ISERUN ENI<br \/>\nAkoonu<br \/>\nAwon iserun  eni tumo si baba-nla eni, ti o se iran eni sile tabi ori eni ti iran kan ti bere. Ko si iran kan ni ile Yoruba ti ko ni awon ti o see nitori pe &#8216;okun ki i gun titi ki o ma ni ibi ti o ti fa wa.<br \/>\nAwon baba-nla wa ti a n toka si yii ti wa nigba iwase, won ti se gudugudu meje ohun yaaya mefa nigba aye  won.<br \/>\nAwon Yoruba gbagbo pe odo ki san ki o gbagbe orisun re, opolopo igba ni won maa n pe oruko baba-nla  fun iyonu  ati aabo nitori pe won gbagbo pe eni to ba ti ku ni agbara nla lati bukun  awon ti won je iran won ni aye.<br \/>\nAkoko odun tabi loorekoore ni a maa n se etutu lati tu awon iserun eni loju fun oore ti won n reti lodo won.<br \/>\nOdoodun ni awon iran miiran maa n bo iserun won tabi nigba ti wahala tabi idarudapo ba wa ninu ebi won.<\/p>\n<p>\u00a0Ebi kookan ni o ni ojubo ti won ti n bo iserun won, o le je agboole tabi ni eyin odi ilu. Iru eyin odi yii le je ibi ti baba-nla won tedo si nigba  iwase.<\/p>\n<p>\u00a0Ogangan ibi ti oku ba kori si ni won ti n se etutu<br \/>\nOrisiirisii ohun jije mimu ni won n bo iserun eni, agbo tabi agutan adie abbl. Won yoo si  ro eje re si oju oori iserun won naa, won yoo da obi, ti o ba si ti yan, o ti  gba niyen, akoko ayeye  ni o maa n je fun gbogbo ebi<\/p>\n<p>\u00a0Ni ile Ijebu Agemo ni  won nse. Awon ni ipinle Eko kii fi Adamu \u2013 Orisa sere.<br \/>\nIla oju, oriki \u2013orile ati isesi iran kookan je eyi ti a fi n da ara wa mo, ti o si n mu iserun eni wa si iranti.<\/p>\n<p>\u00a0Inu oriki-orile ise, ise, iwa, esin, ati eewo iran ni a ti n gbo oniruuru oruko ti an baba-nla wa ti je seyin.<br \/>\nAp<\/p>\n<p>\u00a0Iran onikoyi je iran jagun, eyi si han ninu oriki ati itan iran won, baba \u2013nla won je jagunjagun.<br \/>\nIwa akin hihu ko si fi iran yii sile. Iran aagberi ko fe gbagbe oogun abenu gongo.<br \/>\nIran Olofa kan o je gbagbe ijakadi.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IGBELEWON<br \/>\n<\/strong><\/li>\n<\/ul>\n<ol>\n<li>Ki ni iserun eni tumo si?\n<\/li>\n<li>\n<div>Daruko awon iserun ile Yoruba ti o mo.\n<\/div>\n<p>\u00a0<strong>IWE AKATILEWA<\/strong><br \/>\n\t\t\tAewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>ETO EBI<br \/>\n<\/strong>Ni ile Yoruba, ebi ni a tun n pe ni alajobi tabi molebi. Alajobi ni iya, baba, egbon, aburo ati ibatan eni ni apapo. Eto ebi ni opomulero ti o gbe asa, ise, ati ibara-eni-gbepo awon Yoruba duro. omo nibi-niran ni awon Yoruba. Bi won se tan si ile baba ni won tan si ile iya. <\/p>\n<p>\u00a0Eto ebi bere lati inu ile. Gege bi asa baba ni olori ile, iya ni atele ki o kan awon omo gege bi ojo ori won. Iko kokan ni o ni ipa ti o n ko lati mu ki ife, isokan, laafia ati ajosepo wa ninu ebi.<\/p>\n<p>\u00a0Lara awon ibasepo ti o wa ninu ebi ni:<br \/>\nIse obi si omo<br \/>\nIse omo si obi.<br \/>\nIbasepo laarin omo iya si omo iya<br \/>\nIbasepo laarin Obakan si Obakan<br \/>\nIbasepo laarin idile eni ati baba eni<br \/>\nIpo Baale ati ojuse re<br \/>\nIpo Iyaale Ile ati ise re<br \/>\nIpo Obinrin ile<br \/>\nIpo Orogun<br \/>\nIpo Omo Osu ati ise won<br \/>\nIpo Omokunrin Ile ati ise won<br \/>\nIpo Omobinrin ile<br \/>\nAwon Alejo tabi Alabagbe<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IGBELEWON<\/strong>\n\t\t\t<\/li>\n<li>Salaye awon wonyi: Obakan, Iyekan-eni, Omo Osu, Obinrin Ile ati Omobinrin Ile.\n<\/li>\n<li>\n<div>Ki ni ojuse Baale Ile? Salaye ni kikun.\n<\/div>\n<p>\u00a0<strong>IWE AKATILEWA<\/strong><br \/>\n\t\t\tAewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.<\/p>\n<p>\u00a0LITIRESO<br \/>\nKika iwe ti ajo WAEC yan<br \/>\n<strong>IGBELEWON<br \/>\n<\/strong>1. \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0a. Kin ni iserun eni?<br \/>\nb. Igba wo ni a n bo iserun eni?<br \/>\nd. Kin ni a fi n bo won?<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IWE AKATILEWA<br \/>\n<\/strong>Imo Ede Asa ati Litireso Yoruba  (SS3)  S.Y  Adewoyin 277 \u2013 279<\/p>\n<p>\u00a0<strong>APAPO IGBELEWON<br \/>\n<\/strong><\/li>\n<li>Kin ni  oro-ayalo?\n<\/li>\n<li>Ona meloo ni a n gba lati ya oro lo? Salaye won pelu apeere\n<\/li>\n<li>Salaye awon wonyi: Obakan, Iyekan-eni, Omo Osu, Obinrin Ile ati Omobinrin Ile.\n<\/li>\n<li>\n<div>Ki ni ojuse Baale Ile? Salaye ni kikun.\n<\/div>\n<p>\u00a0<strong>ATUNYEWO EKO<\/strong>\n\t\t\t<\/li>\n<li>Ki ni oro oruko?<strong><br \/>\n\t\t\t<\/strong><\/li>\n<li>Ki ni oro aropo oruko?<strong><br \/>\n\t\t\t<\/strong><\/li>\n<li>\n<div>Ko iyato merin laarin oro oruko ati oro aropo oruko.<strong><br \/>\n\t\t\t\t<\/strong><\/div>\n<p>\u00a0<strong>ISE ASETILEWA<br \/>\n<\/strong><\/li>\n<li>Awon Iserun eni tumo si (a) Baba-nla  eni (b) eni ti o se iran eni sile (d) eni to na omokunrin ile\n<\/li>\n<li>Inu _______ ni a ti n gbo nipa oniruuru oruko idile (a) oriki orile (b) iwure (d) ofo\n<\/li>\n<li>Ojubo iserun eni le wa ni _____  ati (a) Inui le (b)agboole (d) ilu odikeji\n<\/li>\n<li>Ona _____________ ni a le gba ya oro lo ninu ed Yoruba (a) meji  (b) meta (d) merin\n<\/li>\n<li>\n<div>A ya pasito ni pase _____(a) esin (b) eto eko (d) imo ero\n<\/div>\n<p>\u00a0<strong>APA KEJI<br \/>\n<\/strong><\/li>\n<li>\n<div>Kin ni oro \u2013 ayalo?\n<\/div>\n<p>b. Ona meloo ni  a n gba ya oro wonu ede Yoruba<br \/>\nd. Ko irisi awon oro Geesi wonyi sile leyin igba ti a ba ti ya won wonu ede Yoruba<br \/>\nTeacher, Starch, Milk, bread, class, scale, block, trouser, brother, shilling\n<\/li>\n<li>\n<div>Kin ni iserun eni\n<\/div>\n<p>b. Daruko apeere Iserun eni meta nile Yoruba<br \/>\nd. Daruko igba ati ohun ti a si n bo iserun eni.<br \/>\n3. Salaye eto ebi ni kikun.<br \/>\n<strong><br \/>\n\t\t\t\t<\/strong>\u00a0<\/li>\n<\/ol>\n","protected":false},"excerpt":{"rendered":"<p>\u00a0OSE KETA ORO \u2013 AYALO. Inu ede ti a ti n ya oro lo. Ona&#8230;<\/p>\n","protected":false},"author":1,"featured_media":0,"comment_status":"open","ping_status":"open","sticky":false,"template":"","format":"standard","meta":{"footnotes":""},"categories":[1,319],"tags":[],"class_list":["post-4121","post","type-post","status-publish","format-standard","hentry","category-posts","category-second-term-ss3-yoruba"],"aioseo_notices":[],"_links":{"self":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/4121","targetHints":{"allow":["GET"]}}],"collection":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts"}],"about":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/types\/post"}],"author":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/users\/1"}],"replies":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/comments?post=4121"}],"version-history":[{"count":1,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/4121\/revisions"}],"predecessor-version":[{"id":4122,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/4121\/revisions\/4122"}],"wp:attachment":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/media?parent=4121"}],"wp:term":[{"taxonomy":"category","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/categories?post=4121"},{"taxonomy":"post_tag","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/tags?post=4121"}],"curies":[{"name":"wp","href":"https:\/\/api.w.org\/{rel}","templated":true}]}}