{"id":3589,"date":"2023-10-05T12:03:08","date_gmt":"2023-10-05T12:03:08","guid":{"rendered":"http:\/\/localhost\/ecole9ja\/?p=3589"},"modified":"2023-10-05T12:05:12","modified_gmt":"2023-10-05T12:05:12","slug":"week-7-ss2-third-term-yoruba-notes","status":"publish","type":"post","link":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/posts\/week-7-ss2-third-term-yoruba-notes\/","title":{"rendered":"Week 7 &#8211; SS2 Third Term Yoruba Notes"},"content":{"rendered":"<p>OSE KEJE<\/p>\n<p>\u00a0EYA ARA IFO<br \/>\nEya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon.<\/p>\n<p>\u00a0EYA ARA IFO<\/p>\n<ol>\n<li>EYA ARA IFO TI A LE FOJU RI: awon eya ara wonyi ni a le fi oju ri. Apeere: iho imu, kaa imu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo-fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke, erigi isale iwaju ahon, aarin ahon ati eyin ahon, afase, olele, aja enu, ita gogongo, kaa imu.\n<\/li>\n<li>EYA ARA IFO TI A KO LE FI OJU RI: eya ara ifo ti won wa lati inu ikun si inu ofun ti a ko le fi oju ri. Awon ni: kaa ofun, inu gogongo, tan-an-na, komookun, eka komookun, edo-foro, eran edo-fooro, efonha.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\u00a0AFIPE<br \/>\nAfipe ni awon eya ara-ifo ti won wa ni opona ajemohun. Awon ni won n kopa ninu pipe-iro ede jade. Opona ajemohun bere lati oke alafo tan-an-na de iho enu ati imu. Afipe pin si meji: (i) Afipe Asunsi ati (ii) Afipe Akanmole.<\/p>\n<ol>\n<li>Afipe Asunsi: awon afipe wonyi ni won maa n sun nigba ti a ba n pe iro. Apeere: ete isale, eyin isale, erigi isale, ahon, gogongo, olele.\n<\/li>\n<li>Afipe Akanmole: awon afipe yii ki i sun lo si ibi kan ti a ba n pe iro. Apeere: eyin oke, ete oke, erigi oke, aja enu, kaa imu afase.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\u00a0IGBELEWON<\/p>\n<ol>\n<li>Ko afipe asunsi marun-un sile.\n<\/li>\n<li>Ko afipe akanmole marun-un sile.\n<\/li>\n<li>Ko eya ara-ifo marun-un afojuri marun-un sile.\n<\/li>\n<li>\n<div>Ko eya ara-ifo marun-un sile.\n<\/div>\n<p>\u00a0<\/li>\n<\/ol>\n<p><strong>IWE ITOKASI:<br \/>\n<\/strong>Adewoyin S.Y (2014) IMO, EDE, ASA ATI LITIRESO YORUBA fun ile eko girama agba S.S.1 Corpromutt Publisher Nig Ltd. o.i 5-8.<\/p>\n<p>\u00a0EGUNGUN<br \/>\nEgungun je okan pataki lara esin ibile Yoruba. Orisa egungun je orisa ti awon Yoruba fi maa n se iranti awon baba nla won. Ologbojo ni olori egungun. Eku ni won maa n dab o ori won. Igbale ni won maa n gbe eku egunngun pamo si. Irisi won jo tie sin gelede. Orisiirisii aso ni o maa n wa lara eku egungun. Awon elesin egungun ni won maa n je &#8216;oje&#8217; Ojewale. Ojetunde, Ojegbenro &#8230;.<\/p>\n<p>\u00a0IGBAGBO YORUBA NIPA EGUNGUN<\/p>\n<ol>\n<li>Yoruba gbagbo wi pee sin egunfun je esin aseynwwaye\n<\/li>\n<li>Yoruba gbagbo wi pe o je esin lati orun.\n<\/li>\n<li>Awon yoruba gbagbo wi pe egungun je baba nla awon.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\u00a0IGBELEWON<br \/>\nSalaye lori esin egungun.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IWE ITOKASI:<br \/>\n<\/strong>Adewoyin S.Y (2014) IMO, EDE, ASA ATI LITIRESO YORUBA fun ile eko girama agba S.S.1 Corpromutt Publisher Nig Ltd.<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0APAPO IGBELEWON<\/p>\n<ol>\n<li>Salaye lori esin egungun.\n<\/li>\n<li>Ko afipe asunsi marun-un sile.\n<\/li>\n<li>Ko afipe akanmole marun-un sile.\n<\/li>\n<li>Ko eya ara-ifo marun-un afojuri marun-un sile.\n<\/li>\n<li>Ko eya ara-ifo marun-un sile.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>ISE ASETILEWA<\/p>\n<ol>\n<li>Eya ara-ifo ti a le fi oju ri ni (A) oju (B) ori (C) ete (D) edo foro\n<\/li>\n<li>Eya ara-ifo ti a ko le fi oju ri ni (A) edoforo (B) ete (C) eyin (D) eti.\n<\/li>\n<li>Ewo ninu awon wonyi ni o maa n sun ti ba n pe iro? (A) agbon (B) ete isale (C) ete oke (D) eyin oke.\n<\/li>\n<li>Ki ni aso egungun? (A) sapara (B) kenbe (C) eku (D) adiro\n<\/li>\n<li>Esin wo ni o fi igbagbo Yoruba han nipa iye leyin iku? (A) kokumo (B) oro (C) Obatala (D) egungun.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>APA KEJI<\/p>\n<ol>\n<li>Se iyato laarin afipe akanmole ati asunsi pelu apeere.\n<\/li>\n<li>\n<div>Ki ni igbagbo Yoruba nipa esin egungun?\n<\/div>\n<p>\t\t\t\t\u00a0<\/li>\n<\/ol>\n","protected":false},"excerpt":{"rendered":"<p>OSE KEJE \u00a0EYA ARA IFO Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi&#8230;<\/p>\n","protected":false},"author":1,"featured_media":0,"comment_status":"open","ping_status":"open","sticky":false,"template":"","format":"standard","meta":{"footnotes":""},"categories":[1,281],"tags":[],"class_list":["post-3589","post","type-post","status-publish","format-standard","hentry","category-posts","category-third-term-ss2-yoruba"],"aioseo_notices":[],"_links":{"self":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3589","targetHints":{"allow":["GET"]}}],"collection":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts"}],"about":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/types\/post"}],"author":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/users\/1"}],"replies":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/comments?post=3589"}],"version-history":[{"count":1,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3589\/revisions"}],"predecessor-version":[{"id":3590,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3589\/revisions\/3590"}],"wp:attachment":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/media?parent=3589"}],"wp:term":[{"taxonomy":"category","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/categories?post=3589"},{"taxonomy":"post_tag","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/tags?post=3589"}],"curies":[{"name":"wp","href":"https:\/\/api.w.org\/{rel}","templated":true}]}}