{"id":3227,"date":"2023-10-04T13:10:50","date_gmt":"2023-10-04T13:10:50","guid":{"rendered":"http:\/\/localhost\/ecole9ja\/?p=3227"},"modified":"2023-10-04T13:14:59","modified_gmt":"2023-10-04T13:14:59","slug":"week-7-ss2-second-term-yoruba-notes","status":"publish","type":"post","link":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/posts\/week-7-ss2-second-term-yoruba-notes\/","title":{"rendered":"Week 7 &#8211; SS2 Second Term Yoruba Notes"},"content":{"rendered":"<p>OSE KEJE<br \/>\n<strong>Oro \u2013 Agbaso<br \/>\n<\/strong>Akoonu<br \/>\n Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran.<br \/>\n<strong>Oro agbaso:-<\/strong> je siso oro ti a gbo lenu oloro fun elomiran. Iru oro tabi iroyin bee gbodo je eyi to ti koja. Oro agbaso le je ohun ti enikan so nipa wa tabi elomiran. O si le je iroyin ohun to sele nibi kan. Awon wunren atoka oro agbaso ni so, wi, ni, ki, pase, wi pe, salaye, so fun  abbl<br \/>\nTunde ni oun ko ni wa si ipade<br \/>\nSola beere boya a ti jeun<br \/>\nBi a ba n se agbaso, ayipada maa n de ba oro aropo oruko tabi oro aropo afarajoruko, ti eni to n soro ba lo oro aropo-oruko tabi oro aropo-afarajoruko enikinni ninu oro re \u2013 oro aropo \u2013oruko tabi afarajoruko eniketa ni eni to n se agbaso yoo lo. Apeere:<br \/>\nMo ri owo he.<br \/>\nAgbaso- \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0O ni oun ri owo he.<br \/>\nA  ko mo won ri<br \/>\nWon ni awon ko mo won ri<br \/>\nMo fo aso<br \/>\nO ni oun fo aso<br \/>\nAtunse maa n sele si oro-oruko<br \/>\nap<br \/>\nAfo asafo: Eyi  ni ki o ra.<br \/>\nO pase pe iyen  ni ki o ra.<\/p>\n<p>\u00a0IGBELEWON<\/p>\n<ol>\n<li>\n<div>Se agbaran awon afo asafo wonyi:\n<\/div>\n<ol>\n<li>Oye: Seun, se o ti jeun?\n<\/li>\n<li>Obasa: Banjo, bawo ni o se rin lanna?\n<\/li>\n<li>Folake: Suberu fe gbe ise fun mi.\n<\/li>\n<\/ol>\n<\/li>\n<li>\n<div>Se afo asafo awon afo agbaran wonyi:\n<\/div>\n<ol>\n<li>Tunde ni oun fe mo idi ti n ko fi wa.\n<\/li>\n<li>Basiru so pe omo naa ki i wa deede.\n<\/li>\n<\/ol>\n<\/li>\n<\/ol>\n<p><strong>IWE ITOKASI<br \/>\n<\/strong>Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, Asa ati Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. (S.S.S.3)<br \/>\nCopromutt Publishers Oju Iwe 231-233.<\/p>\n<p>\u00a0AROKO PIPA<br \/>\n Aroko je ona ti awon baba-nla wa fi n ba ara won soro laye atijo. Ami ni won fi maa n ranse si eni ti ko si ni tosi. A le fi aroko aye atijo we leta kiko lode oni.<\/p>\n<p>\u00a0ORISII AROKO AYE ATIJO<br \/>\n<strong>Aale<\/strong>: ni ami ti a maa n le lori eru tabi eso. A maa n fi ni kilo fun eniyan pe nnkan ti a ta mo ti ni oluwa ki enikeni ma di ibe.<br \/>\n<strong>Aaga<\/strong>: aaga ni ami ti a ta mo ara igi meji ti a ri mole lati fi kilo fun eniyan lati sa fun ewu.<br \/>\n<strong>Itufu<\/strong>: ni awon nnkan ti o le mu ina wa, ti a gbe seyinkule eniyan lati fi kilo fun iru eni bee pe ki o jawo kuro ninu iwa ika. Bi bee ko won n bow a jo ile re.<br \/>\n<strong>Asewelewe<\/strong>: jija ewe tutu sile ni ikorita bi ami ni lati fi so fun awon ti won dijo n lo si ibi kan pea won ti koja siwaju.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>AMI IPAROKO NI AYE ATIJO<br \/>\n<\/strong><strong>AMI\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ITUMO<br \/>\n<\/strong><\/p>\n<ol>\n<li>Owo-eyo\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0eni naa ti di eni itanu.\n<\/li>\n<li>Ikarahun igbin\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ife nini. Okan re n fa mi.\n<\/li>\n<li>Iye\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0wa kiakia. Ija ti pari. O ti fo lo bi eye.\n<\/li>\n<li>Iye ayekooto\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0sora lati so otito.\n<\/li>\n<li>Aidan\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0wa san gbese re ni kiakia.\n<\/li>\n<li>Ajoku owu\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0iku tabi ewu wa nitosi.\n<\/li>\n<li>Awo Ehoro\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0sa jinna rere. Ewu wa nitosi.\n<\/li>\n<li>Awo oju ilu\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0oro ti kuro ni asiri. Gbogbo aye ti mo.\n<\/li>\n<li>Awe Obi\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0oro ti yanju.\n<\/li>\n<li>Esun Isu\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0dawo ohun ti fe se yen duro.\n<\/li>\n<li>Esuru\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0oro naa ko gbudo su o.\n<\/li>\n<li>Kain-kain, osun\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0iyawo ti bi omo tuntun\n<\/li>\n<li>Obi \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0gbo tie.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p><strong>IGBELEWON<br \/>\n<\/strong>Ki ni itumo awon nnkan woyin ti a ba fi ranse si ni: <\/p>\n<ol>\n<li>\n<div>ooya\n<\/div>\n<ol>\n<li>eja\n<\/li>\n<li>akan\n<\/li>\n<li>obi\n<\/li>\n<\/ol>\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\u00a0<strong>IWE ITOKASI<br \/>\n<\/strong>Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, Asa ati Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. (S.S.S.3) Copromutt Publishers 76-82.<br \/>\nLITIRESO<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0ZT%NY@W) IX!<\/p>\n<ol>\n<li>\n<div>Ki ni oro aropo oruko eni kin-in-ni mesan-an sile.\n<\/div>\n<ol>\n<li>Ko apeere oro oruko eni keji sile.\n<\/li>\n<\/ol>\n<\/li>\n<li>Ko apeere oro oruko eni keta mesan-an sile.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\u00a0ISE ASETILEWA<\/p>\n<ol>\n<li>&#8221;Yemi: mo ti yo bamubamu&#8221;. Afo agbaran gbolohun yii ni   A. o ti yo bamubamu B. mo ti yo bamubamu C. oun ti yo bambamu D. o ti yo bamubamu.\n<\/li>\n<li>&#8221; mo n lo&#8221; afo agbaran gbolohun yii je A. o n lo B. o ni mo lo C. o ni oun lo D. o ti n lo.\n<\/li>\n<li>Tinu so pe oun feran iresi pelu eja tutu. Ki ni afo asafo gbolohun yii? A. mo feran iresi eleja tutu B. o ni mo feran iresi ati eja tutu C. o ni oun feran iresi ati eja tutu D. o feran iresi pelu eja tutu.\n<\/li>\n<li>Yemi ni awon ti pon omi. Ki ni afo asafo gbolohun yii? A. e ti ponmi sile B. a ti ponmi sile C. emi ti ponmi sile D. Yemi ni a ti ponmi sile.\n<\/li>\n<li>\n<div>Ti won ba fi obi ranse si eniyan itumo re ni A. ki iku o bi lori eniyan B. ki eniyan maa tete bo C. ife ti pari D. ki eniyan gbo tie.\n<\/div>\n<p>APA KEJI\n<\/li>\n<li>Ki ni afo asafo?\n<\/li>\n<li>Ki ni afo agbaran?\n<\/li>\n<li>Se alaye: kain-kain, esuru, awo oju ilu.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\t\t\u00a0<\/p>\n","protected":false},"excerpt":{"rendered":"<p>OSE KEJE Oro \u2013 Agbaso Akoonu Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran&#8230;.<\/p>\n","protected":false},"author":1,"featured_media":0,"comment_status":"open","ping_status":"open","sticky":false,"template":"","format":"standard","meta":{"footnotes":""},"categories":[1,257],"tags":[],"class_list":["post-3227","post","type-post","status-publish","format-standard","hentry","category-posts","category-second-term-ss2-yoruba"],"aioseo_notices":[],"_links":{"self":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3227","targetHints":{"allow":["GET"]}}],"collection":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts"}],"about":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/types\/post"}],"author":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/users\/1"}],"replies":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/comments?post=3227"}],"version-history":[{"count":1,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3227\/revisions"}],"predecessor-version":[{"id":3228,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3227\/revisions\/3228"}],"wp:attachment":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/media?parent=3227"}],"wp:term":[{"taxonomy":"category","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/categories?post=3227"},{"taxonomy":"post_tag","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/tags?post=3227"}],"curies":[{"name":"wp","href":"https:\/\/api.w.org\/{rel}","templated":true}]}}