{"id":3019,"date":"2023-10-04T09:21:52","date_gmt":"2023-10-04T09:21:52","guid":{"rendered":"http:\/\/localhost\/ecole9ja\/?p=3019"},"modified":"2023-10-04T09:22:21","modified_gmt":"2023-10-04T09:22:21","slug":"week-8-and-9-ss2-first-term-yoruba-notes","status":"publish","type":"post","link":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/posts\/week-8-and-9-ss2-first-term-yoruba-notes\/","title":{"rendered":"Week 8 and 9 &#8211; SS2 First Term Yoruba Notes"},"content":{"rendered":"<p><strong>OSE KEEJO<br \/>\n<\/strong>AKORI EKO: ATUNYEWO AWON IRO NINU EDE YORUBA<br \/>\n<strong>OSE KESAN-AN<br \/>\n<\/strong>AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI<br \/>\nIro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade.<br \/>\nIdiwo le waye nipa ki ona eemi se patapata, ki iro jade pelu ariwo taki ki o se die ki iro jade ni irorun. Awon iro konsonanti ede Yoruba ni:<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0d, b, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, \u1e63, t, w, y.<br \/>\nABUDA IRO KONSONANTI: Ti a ba fe se apejuwe iro konsonanti nipa abuda, a nilati wo awon ilana wonyi wo ni okookan:<\/p>\n<ol>\n<li>Orison eemi ti a fi n pe iro\n<\/li>\n<li>Irufe eemi ti a lo\n<\/li>\n<li>Ipo alafo tan-an-na\n<\/li>\n<li>Ipo afase\n<\/li>\n<li>Irufe afipe ti a lo\n<\/li>\n<li>Irufe idiwo ti o wa fun eemi\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>Orisun eemi ti a fi pe iro: A nilati so orison eemi ti a lo lati pe iro konsonanti, yala <\/p>\n<ul>\n<li>Eemi edo-foro lati inu edo-foro ni tabi\n<\/li>\n<li>Eemi amisinu ti a seda re wa ni enu\n<\/li>\n<\/ul>\n<p>Eemi edo-foro ni a fi n gbe gbogbo konsonanti ayafi iro \/kp\/ ati \/gb\/ ti a n lo apapo eemi edo-foro ati eemi ti a seda re wa ni enu.<br \/>\nIrufe eemi ti a fi gbe iro jade: A nilati so iru eemi ti a fi gbe iro konsonanti jade: Yala<\/p>\n<ul>\n<li>Eemi amisode;\n<\/li>\n<li>Eemi amisinu; tabi\n<\/li>\n<li>Apapo eemi mejeeji (bi o se ri ti a ba pe iro \/kp\/ ati \/gb\/)\n<\/li>\n<\/ul>\n<p>Ipo alafo tan-an-na: A nilati so ipo tan-an-na ofun wa boya<\/p>\n<ul>\n<li>Ipo imi (fun iro aikunyun) tabi\n<\/li>\n<li>Ipo ikun (fun iro akunyun)\n<\/li>\n<\/ul>\n<p>Ipo ti afase wa: A nilati so boya<\/p>\n<ul>\n<li>Afase gbera soke di kaa imu ni tabi\n<\/li>\n<li>Afase wale fun eemi lati gba kaa enu ati imu jade leekan naa.\n<\/li>\n<\/ul>\n<p>Irufe afipe ti a lo: A nilati fi han boya<\/p>\n<ul>\n<li>Afipe asunsi ni a n lo tabi\n<\/li>\n<li>Afipe akanmole\n<\/li>\n<li>Ipa ti afipe kookan ko nogba ti a ba pe iro konsonanti.\n<\/li>\n<\/ul>\n<p>Irufe idiwo to wa fun eemi ti a lo: A gbodo so irufe idiwo ti o sele si eemi ni opona ajemohun, boya<\/p>\n<ul>\n<li>Ona se patapata ni; tabi\n<\/li>\n<li>Alafo die si sile fun eemi lati koja\n<\/li>\n<\/ul>\n<p>A le wa se apejuwe abuda iro konsonanti ni okookan bayii. Bi apeere: iro \/b\/:<\/p>\n<ol>\n<li>Orison eemi \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0eemi edo-foro ni a lo\n<\/li>\n<li>Irufe eemi\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0eemi amisode\n<\/li>\n<li>Ipo alafo tan-an-na\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0alafo tan-an-na wan i ipo ikun\n<\/li>\n<li>Ipo afase\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0afase gbera soke di ona si imu\n<\/li>\n<li>Irufe afipe\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ete isale (asunsi) pade ete oke (akanmole)\n<\/li>\n<li>Iru idiwo\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211;\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ona eemi se patapata ni sakani ete mejeeji\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>ATE KONSONANTI<br \/>\nAte yii fi gbogbo alaye wa lori owoo konsonanti han ni soki.<\/p>\n<div>\n<table>\n<tbody>\n<tr>\n<td>Ona Isenupe<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>Afeji-ete-pe<\/td>\n<td>Afeyin-fete-pe<\/td>\n<td>Aferi-gipe<\/td>\n<td>Afaja-fe-rigi-pe<\/td>\n<td>Afajape<\/td>\n<td>Afafasepe<\/td>\n<td>Afitan-an-nape<\/td>\n<td>Afafa-sefete-pe<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Asenupe<\/td>\n<td>Akunyun<br \/>\nAikunyin<\/td>\n<td>b<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>d<br \/>\nt<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>g<br \/>\nk<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>gb<br \/>\np<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Aseesetan<\/td>\n<td>Akunyun<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>y<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>w<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Asesi<\/td>\n<td>Akunyun<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>j<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Afunnupe<\/td>\n<td>Aikunyun<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>f<\/td>\n<td>s<\/td>\n<td>\u1e63<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>h<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Afegbe-enu-pe<\/td>\n<td>Akunyun<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>l<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Aranmupe<\/td>\n<td>Akunyun<\/td>\n<td>m<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>n <\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<\/tr>\n<tr>\n<td>Arehon <\/td>\n<td>Akunyun<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>r<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<td>\u00a0<\/td>\n<\/tr>\n<\/tbody>\n<\/table>\n<\/div>\n<p>DIDARUKO IRO KONSONANTI<br \/>\nA le se apejuwe iro konsonanti bayii:<br \/>\n[b]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afeji-ete-pe asenupe<br \/>\n[d]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0konsonanti akunyun aferigipe asenupe<br \/>\n[g]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afafasepe asenupe<br \/>\n[gb]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afafasefetepe asenupe<br \/>\n[f]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsoanti aikunyun afeyinfete afunnupe<br \/>\n[h]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti aikunyun afitan-an-nape afunnupe<br \/>\n[dz]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afajaferigipe asesi<br \/>\n[k]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti aikunyun afafasepe asenupe<br \/>\n[l]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun aferigipe afegbe-enu-pe<br \/>\n[m]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afeji-ete-pe aranmu<br \/>\n[n]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun aferigipe aranmu<br \/>\n[kp]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti aikunyun afafasefetepe asenupe<br \/>\n[r]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun aferigipe arehon<br \/>\n[s]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti aikunyun aferigipe afunnupe<br \/>\n[\u0283]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti aikunyun afajaferigipe afunnupe<br \/>\n[t]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti aikunyun aferigipe asenupe<br \/>\n[w]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afafasefetepe aseesetan<br \/>\n[j]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Konsonanti akunyun afajape aseesetan.<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0IRO FAWELI: Faweli ni awon iro ti a pe jade nigba ti ko si idiwo Kankan fun eemi to n ti inu edo-foro bo.<br \/>\nIro faweli ede Yoruba pin si orisii meji. Awon ni:<\/p>\n<ol>\n<li>Faweli airanmupe:\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0a, e, \u04bf, i, o, \u03d9, u\n<\/li>\n<li>Faweli aranmupe:\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0an, \u04bfn, in, \u03d9n, un\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>Lati se apejuwe abuda iro faweli ede Yoruca, a nilati ye ipo ti awon eya ara ifo meta wonyi wa wo:<\/p>\n<ol>\n<li>ahon\n<\/li>\n<li>afase, ati\n<\/li>\n<li>ete\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>Ipo ti ahon wa: A gbodo se akiyesi<\/p>\n<ol>\n<li>apa kan ara ahon to gbe soke julo ninu enu (boya iwaju, aarin tabi eyin ahon)\n<\/li>\n<li>\n<div>bi apa kan to gbe soke naa se ga to ni enu. Bi apeere, bi a ba pe iro \/i\/:\n<\/div>\n<ol>\n<li>iwaju ahon lo gbe soke jule ni enu\n<\/li>\n<li>giga iwaju ahon feree de oke tente ni enu\n<\/li>\n<\/ol>\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>ATE FAWELI: Ate isaje yii ni so ipo tabi irisi ahon ni enu ti a ba gbe iro faweli kookan jade.<br \/>\nFaweli airanmupe<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0Didaruko Faweli:<br \/>\nA le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii:<br \/>\n[a]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese<br \/>\n[e]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese<br \/>\n[\u03b5]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju perese<br \/>\n[i]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ahanupe (oke) iwaju perese<br \/>\n[o]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) eyin roboto<br \/>\n[\u1d1d]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) eyin roboto<br \/>\n[u]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli airanmupe ahanupe (oke) eyin roboto<\/p>\n<p>\u00a0FAWELI ARANMUPE<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0Didaruko Faweli: A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii:<br \/>\n[\u0101]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli aranmupe ayanupe aarin perese<br \/>\n[\u03b5]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli aranmupe ayanudiepe iwaju perese<br \/>\n[i]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli aranmupe ahanupe iwaju perese<br \/>\n[\u1d1d]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli aranmupe ayanudiepe eyin roboto<br \/>\n[\u1e7b]\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0faweli aranmupe ahanupe eyin roboto<\/p>\n<p>\u00a0AKORI EKO: ERO ATI IGBAGBO YORUBA LORI AKUDAAYA ATI ABAMI EDA<br \/>\nIGBAGBO AWON YORUBA NIPA ASEYINWAYE<br \/>\nAwon Yoruba ni igbagbo ti o jinle ninu aseyinwaye (iyen leyin iku) igbagbo ninu pipada wasiaye eni to ti ku yii wa ni aye atijo bee ni o si wa titi di oni.<br \/>\nNi ona kinni, nibi isinku agba fi ese igbagbo yii mule. Ey ribee nigba ti agbalagba kan ninu idile ba ku (yala okunrin tabi obinrin) ti iyawo omo re ba wa ninu oyun ni akoko naa ti omobinrin naa ba ti mo okunrin tabi obinrin leyin iku baba tabi iya agba oruko ti won yoo so iru omo bee ni (ti o ba je okunrin) Babatunde, Babajide, abbl. Sugbon ti o ba je omobinrin, oruko ti won yoo ma pee ni Yetunde, Yeside, Iyabo, Yewande, Yejide abbl.<br \/>\nOna keji ewe awon Yoruba tun gbagbo pe ti enikan ba ku nigba ti ojo re ni aye ko tii pe lati ku kii lo si orun taara, se ni won yoo wa ibikan tedo si tabi ki won maa rare kiri titi ojo re yoo fipe ni aye ki o to le pada lo si orun. Iru awon ti won ba fi ojo dajo lo bayii ni a n pen i akudaaya tabi akufon<br \/>\nOna keta igbagbo awon Yoruba nipa abiku fi idi iye leyin iku mule. Abiku ni omo ti o ku, ti o tun pada wa si aye, o tun le ku, ki o si tun pada waye ni igba ti o ba wuu. Atigbo nipa abiku ti won ge ika owo re ti o si jepe igbati obinrin to bii ya pada bi omo, ika owo mesan-an ni omo tuntun ti o bi gbe waye. Eyi fihan pe omo akoko iru omo bee ni; Kokumo, Igbekoyi, Malomo, Bamitale, Durorike, Kosoko abbl.<br \/>\nOna kerin, awon Yoruba tun gbagbo pe awon iwin ati egbere wa, atipe eniyan ni won tele ki won to di ebora. D.O. Faganwa fi igbagbo yii han ninu awon iwe itan aroso. Oro eda inu itan iwe re je oro tabi iwin. Inu igi bii igi iroko, igi agbalumo, inu igi ibepe, igi ahusa, agbo ogede ni won ngbe. Won asi maa yipada si eniyan nigba ti o ba wu won. Awon Yoruba tile gba pe won maa n na oja ale. Bakannaa ni awon ogboju ode maa n royin itu ti awon ebora maa n fi won pa ninu igbnigba ti won ba n sode ninu igbo.<br \/>\nOna karun-un, awon Yoruba tun gbagbo pe awon elegbe omo wa. Awon omo elegbe bi eyi maa n yo obi won lenu. Aimoye won ni won maa n lo agbara won lati se obi won ni ibi. Ipese ni won maa n se fun won lati tu won loju. Won ti e maa n ka eewo fun awon obi won ti won ko gbodo lana lati se bii beeko, won yoo yo iya won lenu.<br \/>\nWon tun gbagbo wipe awon eyan to n wo aso egungun o se eniyan lasan pe awon alagbara eyan niwon tabi ole. <\/p>\n","protected":false},"excerpt":{"rendered":"<p>OSE KEEJO AKORI EKO: ATUNYEWO AWON IRO NINU EDE YORUBA OSE KESAN-AN AKORI EKO: ATUNYEWO&#8230;<\/p>\n","protected":false},"author":1,"featured_media":0,"comment_status":"open","ping_status":"open","sticky":false,"template":"","format":"standard","meta":{"footnotes":""},"categories":[1,243],"tags":[],"class_list":["post-3019","post","type-post","status-publish","format-standard","hentry","category-posts","category-first-term-ss2-yoruba"],"aioseo_notices":[],"_links":{"self":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3019","targetHints":{"allow":["GET"]}}],"collection":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts"}],"about":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/types\/post"}],"author":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/users\/1"}],"replies":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/comments?post=3019"}],"version-history":[{"count":1,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3019\/revisions"}],"predecessor-version":[{"id":3020,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/3019\/revisions\/3020"}],"wp:attachment":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/media?parent=3019"}],"wp:term":[{"taxonomy":"category","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/categories?post=3019"},{"taxonomy":"post_tag","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/tags?post=3019"}],"curies":[{"name":"wp","href":"https:\/\/api.w.org\/{rel}","templated":true}]}}