{"id":2698,"date":"2023-10-03T11:47:10","date_gmt":"2023-10-03T11:47:10","guid":{"rendered":"http:\/\/localhost\/ecole9ja\/?p=2698"},"modified":"2023-10-03T11:48:56","modified_gmt":"2023-10-03T11:48:56","slug":"week-8-ss1-third-term-yoruba-notes","status":"publish","type":"post","link":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/posts\/week-8-ss1-third-term-yoruba-notes\/","title":{"rendered":"Week 8 &#8211; SS1 Third Term Yoruba Notes"},"content":{"rendered":"<p>OSE KEJO<br \/>\nAROKO ASARIYANJIYAN<\/p>\n<p>\t\t\t<strong>AKOONU <\/strong>: &#8211;<br \/>\nIha meji ni aroko alarinyanjiyan gbodo ni,iha beeni ati iha beeko.Iha eyi ti a faramo ati eyi ti a ko faramo.Eyi ni wi pe akekoo yoo gbenuso fun egbe kin-in-ni ti o faramo,oun kan naa ni yoo se atako fun eyi ti ko faramo.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Akekoo gbodo soro lori egbe mejeeji bi o tile je pe yoo fi si ibi kan ju ibi kan lo.Akekoo koko gbodo soro lori egbe ti ko faramo lori awon ohu n ti o dara ti o wa nibe,yoo wa soro lekunrere lori iha ti o faramo gbogbo awon ohun ti o ba so nibi ni yoo fibi ohun ti o wa ninu koko eyi ti ko faramo subu,ibi ni yoo ti fi idi iha ti o yan mule.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Akekoo gbodo fi idi iha ti o yan mule ninu igunle aroko re.A ko gbodo so itan tabi pa aalo ninu iru aroko bayii.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ETO INU ARIYANJIYAN<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0       Gege bi ohun ti mo so saaju,nigba ti akekoo ba fe tako ero elomiran nipa koko kan, ohun ti yoo se ni sise-n-tele niwonyi<\/p>\n<ol>\n<li>Ki o toka si ero elomiran naa ni soki.\n<\/li>\n<li>Ki o so idi re ti o fi tako ero naa,eyi gbodo je pelu ekun rere alaye.\n<\/li>\n<li>Akekoo yoo wa gbe ero tire kale ni eseese, ki koko re wa ni ipari ohun ti o ba ko.     \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\n<\/li>\n<\/ol>\n<p><strong>\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ILO EDE<br \/>\n<\/strong>Akekoo gbodo sa awon oro inu gbolohun re lo lona ti onkawe\/oluko yoo fi maa fokan baalo.<br \/>\n    Iru awon gbolohun wonyi dara lopolopo fun ariyanjiyan sise<br \/>\n  -Ero awon kan nip e&#8212;&#8212;&#8212;    sugbon eyi ko ri bee nitori pe<br \/>\n   &#8211; Ati gbo pe&#8212;&#8212;-  bi o tile je pe<br \/>\n   -Awon kan gbagbo pe&#8212;&#8212;&#8211;  sugbon won ti gbagbe pe&#8212;&#8212;-<br \/>\n   -Awon elomiran ro wi pe&#8212;&#8212;&#8212;    sugbon won ti gbagbe pe<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Akekoo gbodo lo akoto ode oni lati gbe ise re kale.<br \/>\nSiwaju si i, owe naa wulo fun ariyanjiyan sise, nigba ti a ba ti lo won lona ti o to ti o si ye.<br \/>\nApeere ori oro aroko alarinyanjiyan ni : &#8211;<br \/>\nOwo legbon,omo laburo.<br \/>\nIyawo kan dara loode.<br \/>\nKiko ede abinibi san ju kiko ede okeere lo.<br \/>\nIse adani mowo wole ju ise akowe lo.<br \/>\nDokita wulo fun ilu ju agbe lo.<br \/>\nIgba eerun dara ju igba ojo lo.<br \/>\nOhun ti okunrin le se,obinrin naale se e.<br \/>\nNje o to ki obinrin abileko maa sise ijoba?<br \/>\nNje o to ki a maa pa awon adigunjale?<\/p>\n<p>\u00a0IGBELEWON<br \/>\n  Se ilapa ero fun ori-oro yii<br \/>\n   Ise adani mowo wole ju ise osu lo.<\/p>\n<p>\u00a0<strong>IWE AKATILEWA<br \/>\n<\/strong>Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, Asa Ati Litireso fun ile Sekondiri Agba S.S. 1. Corpromutt Publihers Nig Ltd  Oju iwe 182-188.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\nASA<br \/>\nASA ISINKU NI ILE YORUBA<br \/>\nAwon Yoruba gbagbo pe gbogbo wa ni a da agbada iku,won a ni &#8216;ma forum yo mi gbogbo wa la jo n lo.&#8217;atomode atagba ko si eni ti ko ni ku,gbogbo wa la je gbese iku.Ki Olorun ko fi iku rere pa ni.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Awon Yoruba gbagbo pe bi eniyan ba ku yoo lo si orun,yala rere tabi orun apaadi.<br \/>\nAWON ONA TI A N GBA SIN ORISIIRISII OKU.<br \/>\nAKOONU : &#8211;<br \/>\nKi Edumare ki o fi iku ire pa gbogbo wa bi a ti n sin oku kookan da lori eni ti o je ati iru iku ti o pa eni bee.Die ninu iru re niwonyii.<br \/>\nEni ti sango pa.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Awon mogba nii se etutu  sisin re.<br \/>\nEni ti sanponna pa\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0inu igbo ni won maa n sin-in si awon adahunse n<br \/>\n                                                                 sii se etutu sisin re.<br \/>\neni ti o ku sinu odo\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0  eti odo ti o ku si ni won maa n sin \u2013in si,awon<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0alawo ni si n se etutu re.<br \/>\neni ti o ku  toyuntoyun\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0awon oloro nii se etutu sisin re.<br \/>\nAdete\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0awon ogbontarigi  adahunse ni i se etutu sisin re,inu<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Igbo ni won a sin-in si, won a si sun gbogbo nnkan \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Ini re.<br \/>\nEni ti o pokunso\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Awon onimole ni i sin in,idi igi ti o pokunso si naa<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ni won o sin in si.<br \/>\nAbuke\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Awon babalawo ati adahunse ni i se etutu sinsin re,\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Inu igbo ni won sin in si, ninu ikoko,won a si sin<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Gbogbo nnkan ini re mo pelu.<br \/>\nBabalawo \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0awon agba awo ni i se etutu sisin oku babalawo<br \/>\npelu eye ti o ga ti won yoo fi se etutu lati yose re<br \/>\nkuro ninu egbe awo.<br \/>\nOde \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0awon ode nii se ayeye oku ode sisin,oro pataki<br \/>\nti Won ni lati se fun un ni sisipa ode ti a mo si &#8216; ikopa ode&#8217; eyi ni etutu ti won maa  n se ki awon eran ti ode naa ti pa nigba aye re ma baa hun un,ki o sile je ki awon ode to ku laye maa ri eranko.<br \/>\nOnilu \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0awon onilu nii se etutu onilu lati yowo elegbe won<br \/>\n  \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0ti o ti ku kuro ninu egbe ki awon to ku le maa ri se.<br \/>\nAlagbede \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Awon alagbede nii se oro igbeyin fun oku alagbede<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0lati yowo re kuro ninu egbe.Inu ile aro ti alagbede<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0naa ti n sise ki o to ku ni a ti maa n saba se etutu<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Ikeyin yii.<br \/>\nYato si gbogbo awon wonyii,awon Yoruba a maa ro oku paapaa eyi ti o ba je oku oroju ti<br \/>\nwon gba pe iku re kii se lasan,awon agba adahunse tabi oloogun ni o maa n ro oku, ki<br \/>\nwon to gbe e si koto, riro yii lo maa je ki o se iku pa eni ti o pa a.   .<br \/>\nIGBELEWON : &#8211;<br \/>\nsalaye ona ti a n gba sin awon oku wonyii; &#8211; i. eni toku somi,ii. Eni ti sango pa. iii. Adete iv. Eni ti o pokunso.<\/p>\n<p>\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0LITIRESO<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0EWI ALOHUN TO JE MO ASA ISINKU<br \/>\n  Ewi alohun-;je ewi ti a jogun lodo awon baba \u2013nla wa,nitori pe awon Yoruba je eya to feran ewi lopolopo,bi won se ni ewi fun asa isinku naa ni won ni ewi atenudenu fun orisiirisii ayeye to ku.<br \/>\n    Lara awon ewi atenudenu ti a ya soto fun isinku ni;<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Oku pipe<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Igbala sisin<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Iremoje.<br \/>\n   Bakan naa ni won le lo awon ewi atenudenu miiran fun ayeye isinku, ki i  se dandan ki o je awon ti a ko soke yii nikan.<br \/>\n          Oku  pipe<br \/>\n      Yoruba ka iku si ohun ibanuje pupo. Nigba ti iku ba de, igbe ekun a gba ile,okiki a gba ode.Awon eniyan yoo bere si pohunrere ekun, won yoo si maa so orisiirisii ohun ti o ba bo si won lenu, lati fi edu okan won han.Iru ekun bayii ti awon agbalagba obinrin maa n sun ti won si maa fi n pe oku bi eni pe ko dide soro ni a n pe ni oku pipe.<br \/>\n      Ohun ti o maa suyo ninu ewi tabi arofo oku pipe ni<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; iwa ati ise eni ti o ku.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 &#8211; irisi re<br \/>\n             &#8211; itan igbesi aye re<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 &#8211; awon aseyori re<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 &#8211; oriki-orile<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 &#8211; ise re.<br \/>\n   Bi eniyan ba teti si oku pipe yoo mo oruko eni ti o ku,awon obi re,oruko awon omo re ati oruko awon aya re(bi o ba je okunrin) tabi oruko oko re(bi o ba je obinrin).Gbara ti oku ba ti ku ni arofo oku pipe yoo ti bere titi di igba ti won yoo sin in.<br \/>\n    Asiko ti enikan ba ku ni a o maa gbo ninu oku pipe bi o se lawo to, bi o se je oninu-un-re to,bi o se ko eniyan mora to abbl.<br \/>\n    Eyi ni apeere oku pipe<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0A a ri ni lode a a beere<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0A a ri ni lode a a beere<br \/>\n            Ki n poloro mi ku,  abo sun ni?<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Abinbolu Akanji lo gbaa n o rii?<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Baba Foyeke,baba Ejire fi mi sile lo sorun alakeji.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Iku gboko lowo mi po o.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Iya nla je mi n o lolugbeja<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Iku pomo Farounbi<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0O lo ba baba to bi i lomo<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Akanbi omo olu-oje<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Omo olomi tutu ese oke.<br \/>\nBi a ba wo apeere oku pipe ti a fun wa yii, a o ri i pe gbogbo awon ohun ti a menuba pata ni o wa nibe.<br \/>\n   Iremoje ni ewi atenudenu ti awon ode maa n lo lati dagbere fun ode egbe won ti o ba ku ati lati yo ese re kuro ninu egbe ode ti aye.<br \/>\n       \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\n<strong>IGBELEWON<br \/>\n<\/strong>    \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Daruko awon koko ti o maa n jeyo ninu oku pipe pelu apeere.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0        <\/p>\n<p>\u00a0<strong>IWE AKATILEWA<br \/>\n<\/strong>Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, Asa Ati Litireso fun ile Sekondiri Agba S.S. 1. Corpromutt Publihers Nig Ltd  Oju iwe 106-112<\/p>\n<p>\u00a0<strong>APAPO IGBELEWON<br \/>\n<\/strong><\/p>\n<ol>\n<li>Daruko awon koko ti o maa n jeyo ninu oku pipe pelu apeere.<strong><br \/>\n\t\t\t\t<\/strong><\/li>\n<li>Ko apeere ewi alohun ti o je mo asa isinku.\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>\u00a0<strong>ISE ASETILEWA<br \/>\n<\/strong>    1.Leta &#8212;&#8212;&#8212; ni a maa n ko si ore,ara,ebi ati ojulumo.<br \/>\n      (a) eni mimo    (b) gbefe   (d) aigbagbefe<br \/>\n    2.Adiresi meloo ni leta si ore wa maa n ni?<br \/>\n      (a) kan    (b) meji   (d) meta.<br \/>\n    3&#8212;&#8212;&#8212;- ni ewi atenudenu ti awon ode maa n lo lati dagbere fun ode egbe won.<br \/>\n        (a)oku pipe   (b) igbala    (d) iremoje.    \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\n    4.Okan lara ohun ti o maa n jeyo ninu oku pipe re ni &#8212;&#8212;&#8212;<br \/>\n        (a)oriki oku  (b) iwa re (d) iye ile ti o ko.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<br \/>\n    5.ojo&#8212;&#8212;&#8212; isinku ni won maa n yo ese obinrin agba kuro ninu ebi.<br \/>\n       (a) keta     (b) kejidinlogun   (d) kejidinlogbon.<\/p>\n<p>\u00a0APA KEJI<br \/>\n    1.Ko leta si ore re,ki o si salaye fun un nipa ile-iwe re titun ti o wa bayii.<br \/>\n     2.Daruko awon ewi atenudenu ti a n lo fun oku pipe.<br \/>\n      b.Salaye koko ti o maa n je jade ninu won pelu apeere\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\t\t\u00a0<\/p>\n","protected":false},"excerpt":{"rendered":"<p>OSE KEJO AROKO ASARIYANJIYAN AKOONU : &#8211; Iha meji ni aroko alarinyanjiyan gbodo ni,iha beeni&#8230;<\/p>\n","protected":false},"author":1,"featured_media":0,"comment_status":"open","ping_status":"open","sticky":false,"template":"","format":"standard","meta":{"footnotes":""},"categories":[1,221],"tags":[],"class_list":["post-2698","post","type-post","status-publish","format-standard","hentry","category-posts","category-third-term-ss1-yoruba"],"aioseo_notices":[],"_links":{"self":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/2698","targetHints":{"allow":["GET"]}}],"collection":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts"}],"about":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/types\/post"}],"author":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/users\/1"}],"replies":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/comments?post=2698"}],"version-history":[{"count":1,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/2698\/revisions"}],"predecessor-version":[{"id":2699,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/2698\/revisions\/2699"}],"wp:attachment":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/media?parent=2698"}],"wp:term":[{"taxonomy":"category","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/categories?post=2698"},{"taxonomy":"post_tag","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/tags?post=2698"}],"curies":[{"name":"wp","href":"https:\/\/api.w.org\/{rel}","templated":true}]}}