{"id":2273,"date":"2023-10-02T11:47:09","date_gmt":"2023-10-02T11:47:09","guid":{"rendered":"http:\/\/localhost\/ecole9ja\/?p=2273"},"modified":"2023-10-02T11:47:40","modified_gmt":"2023-10-02T11:47:40","slug":"week-10-ss1-second-term-yoruba-notes","status":"publish","type":"post","link":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/posts\/week-10-ss1-second-term-yoruba-notes\/","title":{"rendered":"Week 10 &#8211; SS1 Second Term Yoruba Notes"},"content":{"rendered":"<p>OSE KEWAA<br \/>\nORI-ORO-;ISORI ORO-ORUKO<br \/>\nAKOONU<br \/>\n&#8211; oriki<br \/>\n&#8211; orisiirisii oro oruko.<br \/>\n&#8211; ise ti oro oruko n se ninu gbolohun.<br \/>\n&#8211; lilo oro oruko ninu gbolohun.<br \/>\n          Oro \u2013oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa,abo tabi eyan ninu gbolohun.AP.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Baba ko ebe.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Tolu fo aso.<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Mama se isu ewura.<br \/>\nEYA ORO ORUKO.<\/p>\n<ol>\n<li>\n<div>ORUKO ENIYAN : -Oro oruko le je oruko eniyan,eyi ni oruko ti o n toka si ohun ti o je eniyan.Ap\n<\/div>\n<p>-Rotimi<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; Dele<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0-Ahmed<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; Dokita<br \/>\n\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0&#8211; Iyalaje\u2026abbl<br \/>\n 2. ORO-ORUKO ALAISEEYAN: -Eyi ni oruko to  n toka si awon nnkan ti kii se eniyan AP.okuta,iwe, ewure,omi,iyanrin,bata abbl.<br \/>\n3.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Oro-oruko le je ohun elemi : &#8211; Eyi je oruko nnkan ti won ni emi bii eniyan tabi eranko.apaja,eniyan,esin,maalu,alangba,okunrin.abbl.<br \/>\n4.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Oro-oruko le je ohun alailemii: &#8211; Eyi ni awon nkan ti ko ni emi.ap iwe,ile,bata,ewe,igi,abbl.<br \/>\n5.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Oro-oruko le je ohun aridimu : &#8211; Eyi ni awon ohun ti a le fi oju ri tabi fi owo kan.apewa,eja,isu,tabili,sokoto,aga,ewedu,abbl.<br \/>\n6. \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0Oro-oruko le je oruko ibikan :- Eyi ni awon oro oruko ti a le fi ibo se ibeere won.Ap ibo lo n lo? Osodi,Meka,Soosi.<br \/>\n7.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Oro-oruko le je ohun afoyemo : &#8211; Eyi ni awon ohun ti a ko le fojuri sugbon ti a le mo nip aero opolo.Ap ogbon,ilera,ero,ife,alaafia,igbadun,wahala,imo.<br \/>\n8.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Oro-oruko le je aseeka : &#8211; Eyi ni o n toka si ohun ti a le ka Ap. Ile,ilu,eniyan,iwe,tatapupu.<br \/>\n9.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Oro-oruko le je alaiseeka : &#8211; Eyi ni o n tokasi awon ohun ti koseeka  Ap Iyanrin,epo,omi,afefe,gaari,irun.<br \/>\n10.\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 Oro-oruko le je oruko igba : &#8211; Eyi ni oro ti a le lo lati toka si igba ti nnkan sele han.Ap Aaro,ana,odun,irole,oni,ola,ijeta.<br \/>\nISE TI ORO-ORUKO N SE NINU GBOLOHUN.<br \/>\nOna meta Pataki ni a le gba lo oro-oruko ninu gbolohun,o le sise:<br \/>\ni.Oluwa,<br \/>\nii. abo<br \/>\niii. eyan.<br \/>\nOLUWA;ni eni tabi ohun ti o se nnkan ninu gbolohun.ap Baba ko ebe.<br \/>\nBola fo aso.<br \/>\nABO;ni eni tabi ohun ti a se nnkan si,ap<br \/>\nMama se obe<br \/>\nBolu ko leta.<br \/>\nEYAN;ni o maa n se afikun itunmo fun oro-orukoap<br \/>\nMama se obe eja yiyan.<\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0Bola se isu ewura.<br \/>\nOna miran ti a tun le gba da oro oruko mo ni pe<br \/>\nOro-oruko maa n gba oro aropo bii eyan,ap<br \/>\n&#8216;oro yin ni a sese so tan yii.&#8217;<br \/>\n&#8216;ile re ni mo n lo.&#8217;<br \/>\nOro-oruko le se e lo fun sise akiyesi alatenumo ti a ba gbe saaju wunren &#8216;ni&#8217;ap<br \/>\n&#8216;iwe ni mo ra.&#8217;<br \/>\nRira ni mo ra iwe yii.<\/p>\n<p>\u00a0ASA<br \/>\nIPOLOWO OJA<br \/>\nAKOONU<br \/>\n   Ipolowo oja-;je ona ti a n gba lati ke gbajare oja ti a n ta si etigbo awon eniyan lati le ba won ra a.<br \/>\n     Ona meji ni a n gba se ipolowo oja,awon naa ni<br \/>\n   i.ipolowo oja abinibi<br \/>\n   ii. ipolowo oja ode-oni.<br \/>\nIpolowo oja abinibi-;je ona ti a n gba polowo oja ni aye atijo,awon naa ni;ipate,ikiri.<br \/>\nIpolowo oja ode-oni-; je ona ti a n gba polowo oja ni ode-oni,lati le je ki oja ti a n ta ya,apeere ipolowo oja ti ode-oni ni; ipolowo lori telifisan,redio,iwe iroyin,fidio ati inu magasinni.<br \/>\n  \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0IWULO\/PATAKI IPOLOWO OJA<br \/>\n   Gege bi a se mo pe ipolowo ni agunmu owo,opolopo anfaani ni o wa ninu ipolowo oja ti anfaani re ko si se e fi owo ro seyin.<br \/>\n          i.        Ipolowo oja maa n je ki oja ta.<br \/>\n            ii.     O maa n je ki awon eeyan mo nipa oja titun to sese n jade.<br \/>\n               iii.   O maa n je ki ohun ti a fe ra wa ni arowoto wa.<br \/>\n.iv.O maa n je ki awon eeyan mo ibi ti won ti le ri oja ti won fe ra.<br \/>\nORISII  OJA TI A N POLOWO<br \/>\n   ONA TI A N GBA SE IPOLOWO<br \/>\nO fere  je pe gbogbo oja ti a ni ni a maa n polowo,eyi ni die lara awon oja ti a maa n polowo.<br \/>\nOJA\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0IPOLOWO<br \/>\nEfo\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0   E  refo e sebe.<br \/>\nGaari\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0   gaari,olooyo,ayangbe gaari o<br \/>\nAta\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0   E rata e sebe o<br \/>\nIresi\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0   ofe niresi eran lowo<br \/>\nEpo\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0  E repo e sebe.<br \/>\nIru\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0\u00a0 E raru e sebe.<br \/>\nOrisii ogbon ni awon oloja maa n da lati polowo oja won,ki awon eeyan le ba won ra a,ara awon ogbon naa ni<\/p>\n<ol>\n<li>\n<div>Itowo-;Eyi ni pe won a fun onibara ni die ninu oja ti won n ta pe ki o to o wo bi o se ri lenu ap gaari.\n<\/div>\n<\/li>\n<li>\n<div>Isiwo-; Eyi ni pe won a ti ni kekere kan ninu oja yen ti won a maa fi han onibara lati wo o bi o se ri ap eko.\n<\/div>\n<\/li>\n<li>\n<div>Awin-;  Awon oloja maa n ta oja awin fun awon onibarawon lati fi fa oju won mora.\n<\/div>\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>   Orisiirisii ede aponle ni awon oloja maa n lo lati fa oju awon onibara won mora,fun apeere &#8220;e woju obe e muyan.<br \/>\nIgbelewon<\/p>\n<ol>\n<li>\n<div>Daruko awon oja ti a maa n polowo.\n<\/div>\n<\/li>\n<li>\n<div>se ipolowo merin ninu won.\n<\/div>\n<\/li>\n<li>\n<div>Daruko isori oro-oruko marun-un pelu apeere metameta fun ikookan..\n<\/div>\n<\/li>\n<\/ol>\n<p>Iwe Akatilewa<br \/>\n    Iwe imodotun Yoruba fun olodun kin-in-ni o.i 93, 98.<br \/>\nISE ASETILEWA<br \/>\n1.&#8212;&#8212;&#8212;-  ni agunmu owo<br \/>\n  (a)  itowo  (b)  ipolowo    (d) ikiri<br \/>\n2. &#8212;&#8212;- je okan lara ogbon ti awon oloja maa n lolati ta oja won.<br \/>\n   (a) ipate    (b) itowo   (d)  eebu.<br \/>\n3.Okan lara ona ti a n gba se ipolowo oja lode oni ni<br \/>\n   (a) ikiri (b) itowo (d)  redio<br \/>\n4. Mama se eja tutu. Eyan ti o wa ninu gbolohun yii ni<br \/>\n (a)mama   (b)   eja    (d)  tutu.<br \/>\n5. Orisii ise &#8212;&#8212;- ni oro-oruko maa n se ninu gbolohun.<br \/>\n    (a) kan    (b)  meji     (d)   meta.<br \/>\n                APA     KEJI<br \/>\n1,Kin ni ipolowo  oja?<br \/>\nb.Daruko orisii oja marun-un ti a maa n polowo,ki o si polowo won.<br \/>\n2. Salaye ise ti oro-oruko n se ninu gbolohun,pelu apeere metameta fun ikookan.<br \/>\n \u00a0\u00a0\u00a0\u00a0  <\/p>\n<p>\u00a0<br \/>\n\u00a0<br \/>\n\u00a0<\/li>\n<\/ol>\n","protected":false},"excerpt":{"rendered":"<p>OSE KEWAA ORI-ORO-;ISORI ORO-ORUKO AKOONU &#8211; oriki &#8211; orisiirisii oro oruko. &#8211; ise ti oro&#8230;<\/p>\n","protected":false},"author":1,"featured_media":0,"comment_status":"open","ping_status":"open","sticky":false,"template":"","format":"standard","meta":{"footnotes":""},"categories":[1,193],"tags":[],"class_list":["post-2273","post","type-post","status-publish","format-standard","hentry","category-posts","category-second-term-ss1-yoruba"],"aioseo_notices":[],"_links":{"self":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/2273","targetHints":{"allow":["GET"]}}],"collection":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts"}],"about":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/types\/post"}],"author":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/users\/1"}],"replies":[{"embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/comments?post=2273"}],"version-history":[{"count":1,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/2273\/revisions"}],"predecessor-version":[{"id":2274,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/posts\/2273\/revisions\/2274"}],"wp:attachment":[{"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/media?parent=2273"}],"wp:term":[{"taxonomy":"category","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/categories?post=2273"},{"taxonomy":"post_tag","embeddable":true,"href":"https:\/\/ecolebooks.com\/nigeria\/wp-json\/wp\/v2\/tags?post=2273"}],"curies":[{"name":"wp","href":"https:\/\/api.w.org\/{rel}","templated":true}]}}